Content-Length: 261792 | pFad | https://yo.wikipedia.org/wiki/P%E1%BB%8D%CC%81rt%C3%BAg%C3%A0l

Pọ́rtúgàl - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Pọ́rtúgàl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orílẹ̀òmìnira Pọ́rtúgàl
Portuguese Republic

República Portuguesa
Orin ìyìn: "A Portuguesa"
"The Portuguese Hymn"
Ibùdó ilẹ̀  Pọ́rtúgàl  (dark green) – on the European continent  (green & dark grey) – in the European Union  (green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Pọ́rtúgàl  (dark green)

– on the European continent  (green & dark grey)
– in the European Union  (green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Lisbon
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPortuguese
Lílò regional languagesMirandese1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2007)
96.87% Portuguese and 3.13% legal immigrants (Cape Verdeans, Brazilians, Ukrainians, Angolans, etc.)[1]
Orúkọ aráàlúPortuguese
ÌjọbaOrílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
• Ààrẹ
Marcelo Rebelo de Sousa
António Costa
Eduardo Ferro Rodrigues
Formation 
Conventional date for Independence is 1139
• Founding
868
1095
24 June 1128
• Kingdom
25 July 1139
5 October 1143
23 May 1179
1 December 1640
13 February 1668
• Republic
5 October 1910
• Democracy
25 April 1974
Ìtóbi
• Total
92,090 km2 (35,560 sq mi) (110th)
• Omi (%)
0.5
Alábùgbé
• 2011 estimate
10,647,763[2] (77th)
• 2011 census
10,555,853[3]
• Ìdìmọ́ra
115/km2 (297.8/sq mi) (96th)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$247.037 billion[4]
• Per capita
$23,222[4]
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$229.336 billion[4]
• Per capita
$21,558[4]
Gini (1997)38.5[5]
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.795[6]
Error: Invalid HDI value · 40th
OwónínáEuro ()2 (EUR)
Ibi àkókòUTC0 (WET3)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (WEST)
Irú ọjọ́ọdúndd-mm-yyyy, yyyy-mm-dd, yyyy/mm/dd
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù351
Internet TLD.pt4
  1. Mirandese, spoken in some villages of the municipality of Miranda do Douro, was officially recognized in 1999 (Lei n.° 7/99 de 29 de Janeiro), since then awarding an official right-of-use Mirandese to the linguistic minority it is concerned.[7] The Portuguese Sign Language is also recognized.
  2. Before 1999: Portuguese escudo.

Pọ́rtúgàl (Gbígbọ́i /ˈpɔrʉɡəl/ Pọrtugí: Portugal), lonibise bi Orileominira Portugal (Pọrtugí: República Portuguesa[8]), je orile-ede to budo si apaguusuiwoorun Europe lori Penisula Iberia. Portugal ni orile-ede to sunmo apa iwoorun julo ni Europe, be sini o ni bode mo Okun Atlantiki ni iwoorun ati ni guusu, bode mo Spain ni ariwa ati ilaorun. Awon isujo erekusu inu Atlantiki, eyun Azores ati Madeira je ara Portugal. Orile-ede yi gba oruko re lati ibi oruko ilu re totobijulo keji, Porto, ti oruko Latini re je Portus Cale.

Ori ile to wa ninu bode Orileominira Portugal loni ti je titedo leralera lati awon igba iwaju itanakole: latowo awon Gallaeci ati awon Lusitanians, o bo si inu Ileobaluaye Romu be sini awon eniyan elede Jemani bi Suevi ati awon Visigoths na tedo sibe, ni orundun 8k awon Mauri bori ibe. Nigba Reconquista awon Elesin Kristi, Portugal seda ara re bi ileoba alominira, tori ni won se unpe bi orile-ede-ajoba togbojulo ni Europe.[9]

Ni orudnun 15k ati 16k, ntoripe o lewaju Igba Iwari, Portugal di ileobaluaye to nile kakiri Afrika, Asia, Oseania, ati Gusu Amerika, lati di ikan ninu awon alagbara itokowo, oloselu ati ologun lagbaye. Ileobaluaye Portugal ni ileobaluaye akariaye akoko ninu itan,[10] ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon obaluaye alamusin Europe. Sibesibe, ipo orile-ede ti je riresile gan titi to fi di orundun 19k, agaga leyin ilominira ile Brasil, to je imusin totobijulo re.




  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named ine.pt
  2. Pordata, "Base de Dados Portugal Contemporâneo". Accessed on March 7, 2011.
  3. http://www.ine.pt/scripts/flex_v10/Main.html
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Portugal". International Monetary Fund. Retrieved 6 May 2011. 
  5. "Gini Index". World Bank. Retrieved 2 March 2011. 
  6. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  7. The Euromosaic study, Mirandese in Portugal Archived 2007-03-13 at the Wayback Machine., europa.eu – European Commission website. Retrieved January 2007.
  8. (Potogí) Portal do Governo[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. Brian Jenkins, Spyros A. Sofos, "Nation and identity in contemporary Europe", p.145 Routledge, 1996, ISBN 0-415-12313-5
  10. Melvin Eugene Page, Penny M. Sonnenburg, p. 481








ApplySandwichStrip

pFad - (p)hone/(F)rame/(a)nonymizer/(d)eclutterfier!      Saves Data!


--- a PPN by Garber Painting Akron. With Image Size Reduction included!

Fetched URL: https://yo.wikipedia.org/wiki/P%E1%BB%8D%CC%81rt%C3%BAg%C3%A0l

Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy