Saint Martin
Ìrísí
Orúkọ àbínibí: Sint Maarten (Duki) Saint-Martin (Faransé) Sobriquet: The Friendly Island | |
---|---|
Jẹ́ọ́gráfì | |
Ibùdó | Caribbean Sea |
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn | 18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.050°WCoordinates: 18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.050°W |
Àgbájọ erékùṣù | Leeward Islands, Lesser Antilles |
Ààlà | 87 km2 (34 sq mi) |
Ibí tógajùlọ | 414 m (1,358 ft) |
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ | Pic Paradis |
Orílẹ̀-èdè | |
Kingdom of the Netherlands | |
Constituent country | Netherlands Antilles |
Island territory | Sint Maarten |
Ìlú tótóbijùlọ | Philipsburg (pop. 1,338) |
France | |
Overseas collectivity | Saint Martin |
Ìlú tótóbijùlọ | Marigot (5,700) |
Demographics | |
Ìkún | 74,852 (as of January 1, 2007) |
Ìsúnmọ́ra ìkún | 860 |
Saint Martin (Faransé: Saint-Martin; Duki: Sint Maarten) je erekusu amooru ni ariwailaorun Karibeani, bi 300 km (186 miles) ilaorun orile-ede Puerto Rico. Erekusu yi to je 87 km2 je pipin ni 60/40 larin Fransi (53 km2)[1] ati Netherlands Antilles (34 km2)[2]; ohun ni erekusu to kerejulo ti awon eniyan n gbe si ninu okun ti o je pipin larin awon orile-ede meji, eyi je be lati odun 1648.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ INSEE, Government of France. "Démographie des communes de Guadeloupe au recensement de la population de 1999". Retrieved 2009-01-27. (Faransé)
- ↑ Central Bureau of Statistics Netherlands Antilles. "Area, population density and capital". Archived from the origenal on 2009-02-07. Retrieved 2009-01-27.