AFOLABI
AFOLABI
AFOLABI
ibikeji olodumare
a -je -ju Oogun
Obiriti,A -p ijo-iku-da
Oluwa mi A-to-i-ba-j awe
Oro a-bi-ku-j ibo
Oluwa mi ,Ajiki
Ogege a- gb aye-gun,
Odudu ti ndu ori emere
A-tun-ori-ti-ko-sunwon se
A-mo-i-ku
Olowa aiyere
Agiri ile llogbon
Oluwa mi amoimotan
A ko mo tan kose
A ba mo tan iba se be.
EYIOGBE
Odu EYIOGBE speaks of ligth good general welfare victori over enemies,spiritual awakenings long life
and peace of mind
EYIOGBE is the most important odu.it symbolizes the masculine principle and is therefore regarded as
the father of the odu.In the fixed order of orumila eyiogbe occupies the firt position.
In eyiogbe the two sides of the odu are identical ogbe is on both the right and the left side.The odu should
be called ogbemeji,but it is universally known as eyiogbe becau-se eji also means two.There is a balance
of forces in eyiogbe which is always a good omen.
During a divination session the client for whom eyiogbe is divined looking for peace and prosperity.The
client has consulted ifa because he or she want children or wishe to embark on a new project.Ifa says
that if the client makesan offering.all the client’s
demands will be met and all his or her undertakings will be successful.Sacrifice is needed to gain victory
over enemies who might be blocking the client. If he or she has been working without progress or trading
without profit.Ifa predicts prosperity or wealth if the person will make the necessary sacrifices.In eyiogbe
ifa predicts olng life provided the client takes good care of his or her health.
People incarnated by oduneyiogbe must always consult the ifa oracle before making any important
decision in life
-OWO T’ARA
ESE ‘ARA
OTARATARA LO DIFA F’ ELEREMOJU’ TI ISE IYA
AGBONNIREGUN
WON NI KI O RU
ABO, ADIYE MEJI, EYELE MEJI ATI
ALESAN EGBERINDILOGUN OWO
KIOFIBO IFA OMO RE
WON NI UWA RE A S ‘URE
O GBO O RU.
The hands belong to the body
the feet belong to the body
Otaratara divined ifa oracle for eleremoju
the mother of agbonniregun
she wa asked to sacrifice
two herns two pigeons and thirty two hundresd cowries
to be used in appeasing her child’sifa
They said her life would be prosperous
she obeyed and made the sacrifice.
Owo t’ara ese t’ara and otaratara arethe names of the three diviners who consulted the ifa oracle for
eleremoju the mother of agbonniregun(one of orumila ‘s praise title).Elemoju was grappling with problems
she agreed to sacrifice and appease her child’s ifa (ikin ifa sixteen palm nust) she became prosperous
because she sacrificed
the things ifa prescribed.
Sacrifice plays an essential role in the yoruba system of belief and traditional religion, In order to live long
and peacefully on earth,human beings are expected to make the necessary acrifices that will attract good
fortune and ward off misfortune.
-OTOTOOTO
OROROORO
OTOTO LI AI J’ EPA
OTOTO LI AIJE IMUMU
TORITIRU L’ AFI NFE BA MARKIN
L’ O DIFA F’ AGBONNIREGUN
WON NI KI O RUBO A RE
KO TILE NIIMO IYE OMO RE L’ OJU RE ATI LEHIN RE PELU
WON NI KI O RU
EWURE ATI EWE IFA
B’ OBA RUBO KI A SE EWE IFA FUN UN KI O
FUN AWON IYAWO RE JE
OGBO O RU
EWE IFA (lo ewe yenmeyenme agbonyin)
irugba tabi ogiri pelu iyere se won po pelu okun-omo inu ewure naa
ati ohun ise be ti o ku.
gbe ikoko obe naa siwaju ite-ifa
ki awon iyawo re jee nibe
nigbati won jee tan
won (bimo) re pupo.
OTOOOTO
OROROORO
Separately we eat groundnut
separately we eat imumu (special nut)
we are head over heels in love with oba makin
they all divined for agbonniregun
yhey said if he sacrificed he would not even
know the number of his children both during
and after his life
he was asked to sacrifice
a she-goat and ifa leaves
if he offeered the sacrifice,he was to cook ifa leaves
for his wiwes to eat
he obeyed and sacrificed
ifa leaves:grind yenmeyenme(agbinyin)leaves irugba,
or ogiri(condiments)
cook them together with the goat’s fallopian tubes
place the pot of soup in front of the ifa throne and
allow his wives to eat it there
when they finished eating it,they had a lot of children.
Agbonniregun’swiwes were finding it hard to get pregnant and produce children.The five diviners who
divined ifa for agbonniregun emphasized the importance of sacrifice.They said if he agred to sacrifice,he
would have many children during his life and after his death.In addition,the diviners had to employ their
knowledge of traditional medicine to cook agbonyin leaves with the fallopian tubes of the sacrificed she-
goat.This medicine was eaten by agbonniregun’s wives before he could have the children predicted by
ifa.
-OKUNKUN-BIRIMUBIRIMU LI O DIFA F’
ENIUNKOKUNJU
WON NI KOSI ENITI O MAA FI OORE SE TI KO
MAA FI IBI SUU
A NIKI O RU
ADA ATI AKASO
O KO KO RU
ENIUNKOKUNJU-ORUKO TI A NPE AGBE
GBOGBO OORE TI OGEDE SE F’ AGBE
KO KUN LOJU
BIBE NI AGBE BE OGEDE LORI NIKEHIN.
Ifa often apeaks in parables.This story portrays a relationship between the banana (ogede),personified as
someone who was kind to the farmer (agbe), an ingrate who returned kindness with evil.no matter how
great the relationship is the banana is
destroyed in the end.
In ancient times anyone incarnated by this odu might be beheaded at the end of his or her life on earth.In
modern times,it refers more to losing one’s head ‘’ and paying a great cost.
OYEKUNMEJI
IWO OYE
EMI OYE
OYE MEJI LI O DIFA F’ OLOFIN
WON NI
MEJI A SE’ TAN AWON OMO RE TI O MAABI
SUGBON KIOMA BINU NITORIPE WON A RI RE
WON NIKI O WA RUBO
ASO KELEKU ,KI AWONOMO NA MAFI BO RA
O GBO O RU.
-JIJI NI MO JI
MO B’ OMODE WEREWERE
MO BERE ISALU AYE
MO B’AWARE SOKOSOKO
MO BERE ISALU ORUN
ORISA -NLA NLO SODO ORUMILA
O NI: AWON OMODE RE TI OUN NKO LO SI
AYE YI
OTUTU MAI DEE
EFORI MAI DEE
EDUNRA ATI BEEBEE MAI DEE
KINI KI OUN MAASE FUN WON
ORUMILA Y KIOTE ODU OYEKUNMEJI
NI IYE-IROSU
KIO JA ASESEYO PEREGUN KI O LOO
KI O PA WON PO MO ORI
KI O MAA FI PARA FUN WON
PEREGUN SUSU A D’ OMI PA’ NO IKU
PEREGUN-SUSU A D’ OMI PA’ NO ARUN.
IWORIMEJI
-MUJIMUWA
AWO OPAKERE LI O DIFA F’ OPAKEERE
O NIKI O RUBO
KI O MAA BA SAISAN
EBO. OGUN IWO PELU OGUN EYELE
O GBO O RU
O SE EWE IFA FUN UN
KI O FI FO ORI
KI O SI FI IFA RE
O NI OPAKERE KO MAA SAISAN.
IDIMEJI
-EMI ENI-ODI
IWO ENI-ODI
LI O DIFA F’ ODI NIGBA OTE
WON NI:OWO ODI A KA ‘LU
NITORINAA KI O RU
OJA IDIMO MEJI
O GBO O RU.
IROSOMEJI
-OLIYEBE LI O DIFA FUN INA
OLIYEBE LI O DIFA FUN EYIN
OLIYEBE LI O DIFA FUN IKO
A NIKI OKOOKAN WON WA RUBO
EMI (AGBAFI)IFI ATI ASO OFEEFEE
IKO NIKAN LIO GBO EBO TI ORU
NIGBATI BABA WON KU (OLOYE NI BABA WON)
WON FI INA LE’ YE
OJO DE O PA A
WON FI EYIN LE’ YE
OJO DE O PA A BAKANNA
WON FI IKO LE’YE
NIGBATI OJO DE
IKO FI ENI RE BORI
OJO DA O KA ENI RE’KURO
IKO KO KU .
-OKAKARAKA-AFOWOTIKU IDASEGBEREGBEREW’AKO
LI O DIFA FUN IROSU
NIGBI IROSU MI LA BIMO
WON NI AKO-OMO LI O MA BI YI
NITORI KO NI RI OWO FI WO OMO NAA
SUGBON BI O BA NI KI OUN(irosu) RI OWO
FI WO OMO NAA
KI (irosu)O WA RUBO
IGBI MEJI
O KO KO RUBO
OWONRINMEJI
-GOOROMAAFIYUN,GOOROMAAFIBO
LI O DIFA FUN ARUNLOJO ERANKO
NIGBI WON MI LOSAJO
A NIKI WON RU
ASO DUDU
WON KO WON KO RU
OLOGBO NIKANSOSO LI O RUBO NINU WON
NIGBI WON D’ AJO TI WON NRE
AAWON AJE NI WON BA PADE
-OLOIREKOIRE,OLOORUNKOORUN
LI O DIFA FUN OPAKETE
NLO KAN ORILE OMOBIBI
WON NI KO RU
IGBA IKOTI,IGBA ABERE,IGBA EKU ATI IGBA EJA
OPEKETE GBO O RU
O RE GEGEBI IFA TI WI.
OBARAMEJI
-OSUNSUN-IGBO-YI-KOS’OJE,OBUROKOS’EJE
LI O DIFA FUN WON L’ALADE OWA
A NIKI WON RUBO
KI WON LE RI ALEJO WA LE YE
OHUNKOHUN TI BABALAWO BA FE NI EBO
WON GBO WON RU.
OSUNSUN-IGBO-YI-KOS’OJE OBUROKOS’EJE
LI O DIFA FUN SAKOTO NIGBI OUN MI LO SILU OWA
WON NIKI O RU
EYELE,AGO-ALA,AGUTAN ATI AKARA META
O GBO O RU
AWON BABALAWO NI:AKARA NAA,JIJE NIKI
O JE WON KI O MA SE KO WON FUN ESU
BI O TI NLO O KO AKARA
NAA L’ OWO O DE IWAJU ESU KINI
O NA OWO AKARA KAN SII
O NI BI OUN BA MU AKARA YI FUN UN
ESU NAA YOO FI EJI PA OUN DE ILU WA
O FI AKARA NAA S’ENU O JEE
BI O TI NLO O PE O TUN DE IDI ESU
KEJI ONA OWO AKARA KEJI SII
OTUN WI BI O TIWI NIDI ESU KINNI
O KI AKARA NAA S’ ENU O JEE
O TUN DE IDI ESU KETA NI KETE KI OUN
TOO YO SI ILU OWA
O NA OWO AKARA EKETA SI ESU NAA
GEGEBI OUN TISE NI AKOKOBERE
O SI JE AKARA NAA
ESU WA BINU WAYI O O SI FI EJI (ojo)
PAA TITI OUN FI DE ILU OWA
AWON ARA ILU OWA WA MU ALEJO YI
WON FI JOBA
AWON AWO NAA TI SO FUN WON TELE NI
ILU OWA PE
ENITI O NBOWA LE ‘YE.EJI LI O MAA PAA WO ILU.
OSAMEJI
-OKAN-ATEGUN-KOSE-IRODE’LE
LI O DIFA F’ ORUMILA
NIGBI OUN MI LO FE OLUYEMI
TIISE OMO OLOFIN
WON NI:BIOBANI OUN NIKANSOSO,OLA RE A GA
ABO,ADIE MEJI EWURE MEJI ATI EGBERINDILOGUN OWO LI
EBO.
-OMIPENSE-AKODUN-KORO LI O DIFAF’OGUN
MI A GBE OGUN LO JA ILU OTA RE
WON NIKI O RU
AGBE-EMU ESUN ISU ATI EPO
OGUN KO KO RU
AWON BABLAWO NI IFA WIPE
LATI OHUN BOWALE NI WON TI MAAGBE
INKAN BURUKU FUN UN JE NITORI
AIRUBO RE
O DE OHUN O JA O SEGUN BI O TI
NYIPADA BOWA ILE OKAN NINU AWON
IGBEKUN RE WA FII ESUN-ISU LOO
O GBAA O JEE ISU NAA HASII L’ ORUN
TOGEEGEE TI KO LE SE-I-GBEMI DARADARA
NIGBEHIN GBOGBO RE KO TUN LE SORO MO
BIOBA SORO SII ORI AND OWO LIOFI
NDAHUN TIBI ONH.
OTURUPONMEJI
ATI EWE IFA (ewe okunpale ati abo-igbo tabi agbosawa ati beebee
ni ao lo fun sise ni obe fun jije eniti a da ifa yi fun
tabi eniti o fe lati loo ki oun le ni aasiki)
BIO BA JEE TAN ENITI O JEE NAA FI
EDUN-AIRA LE ORI IFA RE.
OTURAMEJI
IRETEMEJI
OSEMEJI
OFUNMEJI(ORANGUNMEJI)
OGBE YEKU
-AWOD’ORO-AWO-OMODE IKA-O-TAN-BORO-AWO-
AGBALAGBA
EERETOKEREPAKESE-IJAM’ESE.
A DIFAF’ALAGEMO-IJAM’ESE
WON NIKI O RU
EGBAAWA OWO IGBA EYELE ATI ONIRUURU ASO
O GBO O RU
AWON AWO SI SE EWE IFA FUN UN
ALAGEMO WA RANSE SI OLOKUN PE
KIAKII F’OUN SE O OUN BOWA BAA PESI
ODUN ASO TI OLOKUN MAA LO TI
OUN KO NIILO IRU RE GEGE O
OLOKUN NI:HEN ALAGEMO NILE-ELE
O NI O DI IGBATI O BA DE IHIN WA BA OUN NA OJO KO
ALAGEMO DE
LOKUN BERESII LO ASO
IRU ASO TI OLOKUN BA LO ALAGEMO ALOO
WON JIJO LO ASO TITI
NIGBOOSE OLOKUN WABINU O NI OUN
YOO DI ONA TI ALAGEMO YOO GBA PADA
SO ILE RE O LO BE AWON OSO AND AJE
LOWE TII KI WON BA OUN SE IDIWO
FUN UN LI ONA-AJO SI ILE RE
ALAGEMO TUN TO BABALAWO LO PE
KINI OUN IBA SE Y ONA-AJO OUN SILE LE DARA
WON NIKI O RUBO
ENI-AGBAFI IGBA-EWO ATI ONIRUURU
INKAN MIRAN
O GBO O RU
WON SE EWE IFA FUN UN WON SI KOO
LI ORIN TI OUN YOO MAA KO BAYI
OSO IBE E JOWO MI
AJE IBE E JOWO MI
BI IGUN BA J’EBO AJOO ‘GBA
ATI PE KI O NA ENI RE SI OJU OMI
KIOGUN LE ORI ENI NAA
ALGEMO SE GEGEBI IMORAN AWON
BABALAWO RE O SI BOWALE.
OYEKULOGBE
WON NIKI
OMO-NLE RU:EIYELE MERIN KI O BAA LE RIBI RER JOKO SI
O RUBO
WON NIKI ORO RUBO KIOMA BAA GBA IBAKALE BUBURU TI O
MI
A MAA WAA NI DI S’ODE
AKUKO-ADIYE KAN NI EBO ORO EYINI NI OGIRI KO RUBO.
OGBEWEHIN
-OGBEWEHIN-FF-AEJO-MBO OGBARA.EJIMA-
TOTO
A DIFA F’OGBE
NLOS’ODE IWORI
WON NIKI O WA RUBO
OBUKO META AKUKO-ADIE META ASO TIOWA NI ORUN
RE ATI ORIDAN EKU KAN(kiomu eku naa si iduro lehin esu)
NITORIPE O MAA B’ORO DE ATI PE KI ORO
NAA MA BAA FOO
O GBO O RU
-OGBEHOFAAFAA A DIFA FUN ALUKUNRIN
(kanna-kanna)
WON NIKI
O WA FI ASO MEJI KAN BAYI(okan dudu ekeji funfun)
TIOWA LOWO RE RUBO PELU OBUKO ATI
AGBO KIOMA BAA SINWIN ATI BIOBAFE KI AWON
AWO SE EWE IFA FUN OUN
EWE IFA NAA(biobarubo)
FI EJE OBUKO TELE IKOKO KIOTOO KO EWE(ogbo ati ewe
esusu)
MASINWIN LEE BU OMI SII KIOMA FIWE
ALUKUNRIN KO KO RU
AWON TI IFA YI BA BI A MAA SINWIN
IWORIBOGBE
OGBEDI
KUKUTE-AGBON KOROJIJI LI O DIFA F’OGBE
OGBE NLOSOKO ODE
WON NIKI
O WA SEBO KIOMA RIBI AKAMO LOHUN
OBUKO META,AKUKO METE EGBAA META OWO
OGBE KO KO RU
O DE OKO-ODE TAN OJO DE BIOTI NSURE LO
O RI IHON KAN TI O GBORO, O SEBI IHO-IGI TABI
OKITI KAN NI,O BOSINU RE KO MO PE ERIN LIOFE IDI SILE
ERIN PA IDI DE MOO
BEE NI OUN KORI IBITI YOO GBA JADE MO
AWON ENIYAN RE BERESII WAA,LEHIN IGBA
PIPE TI WON
KO RII WON LO SE EBO TI OUN KOSILE
ERIN WA YAA MO IGBE
NJE WON NI:OGBE TI O TI IDI BO
KI A MAA PEE NI OGBEDI.
IDIGBE
-BABA-AKIKIBITI BABA-AKIKIBITI
LIO DIFA F ORUMILA
NIGBI IKU NWIPE OUN NBO NI ILE RE TI ARUN
NWIPE OUN NBO NI ILE RE
WON NIKI O O GUN SIGIDI AMONU MEJI
KIOFI IGBA EERU GUN WON LARA
KIOFI AGADA IGI LE WON LOWO NI OKANKAN
KIOPA OBUKO KAN KIODA EJE RE SI WON L’ARA
KIOGBE OKAN SI ENU-ONA IWAJU-ILE
KIOGBE EKEJI SI ENU-ONA EHINKULE
ORUMILA GBO O RU
O SI SE GEGEBI IFA TI SO FUN UN
IKU DE ENU-ONA IWAJU-ILE O KI SIGIDI YI BAYI
BABA-AKIKIBITI,BABA-AKIKIBITI
OJOBI ONA KURO F’ AWO LONA K’AWO RIBI LO,KO DAHUN IKU
PADA
O LOSI ENU-ONA KEJI O NWI BAKANNA
ARUN DE O WI BAKANNA,KO DAHUN
BAYI NI ORUMILA SE TI ARUN KO LE WOLE TOO.
OGBE ROSU
IROSU-OGBE
-OKITI-BAMBA-TIIPEKUN-OPOPO LI O DIFA
F’OLOFIN.
A NIKI O WA RUBO KI OGBE LE YE ORIWIWON LODO RE.
AKUKO META ARABA IYAN META
ATI OBE NI EBO .
O GBO O RU.
OKITI-BAMBA-TIIPEKUN-OPOPO divined ifa for olofin.
He was advised to offer sacrifice so that ogbe would give
him good companions.
Three coks bowls of pounded yam,
and soup should be offered.
He performed the sacrifice.
OWONRINSOGBE
OGBE ‘BARA
OBARABOGBE
OGBE KANRAN
OKANRANSODE
KUKU-NDUKUN, PERE-INOKI.
A DIFA FUN WON I’EGUN MAJO
I’WON A N’ORO YEYE.
ELEDE MERIN OKE MERIN OWO ATI AGBA OTI MERIN NI
EBO.
WON GBO WON RU.
IBINU AO ALARA LI O DIFA F ALARA, EDOFUFU AWO AJERO LI
O DIFA F ‘AJERO, PELETURU AWO ORANGUN LI O DIFA
F’ORANGUN, IFA Y WON MAA FI INKAN KAN RANSE SI WON
MAMA KO O. O PE DIE LEHIN EYI, WON FI EEPA KOKO (EWE
KOKO TIOTIGBE) TI A DI
RANSE SI ALAARA ALARA BINU O NI: EEPAKOKO NI IYA OUN
RI FI RANSE SI OUN NINU GBOGBO INKAN TI O WA I’AVE VI: O
KOO. IYA WON SI TUN FI RANSE SI AJERO. AJERO TUN KOO.
NI IBINU WON MUULO SI
ODO ORANGUN ORANGUN GBAA, OTUU WO. O BA ILEKE NINU
RE.
ORANGUN SA TI RUBO TI BABALAWO RE YAN FUN UN.
ORANGUN TI RU:
ESO ERU EYELE ATI EGBAAJO OWO. ORANGUN SIN IKARUN
KAN NINU WON O FI RANSE SI ALARA PE KI O RAA NITORIPE
OUN RII PE O BAA
MU ALARA RAA.OTUN SIN IKARUN EKEJI O FI RANSE SI AJERO
PE KI O RAA. O SANWO NITORIPE ORANGUN
OHUN DIDARA DU NI WON SE RAA. O SI FI AWON ILEKE
IYOKUN PAMO FUN ILO TI ARA RE.
OGUNDABEDE
OSA’GBE
ESUMARE ABIDI-DODODO
LI O DIFA F’OGBARA-OJO
A NIKI O WA RU
OKO,ADA ATI OBUKO KI AWON OMO ARAYE MA BA MAA DARI
RE
SINU IGBO
O GBO EBO KO MAMA RU
OUN NI OMO ARAYE BERESII DARI SE SINU IGBO
NIGBATI O WA RUBO NI IKEHIN NI AWON OMO
ARAYE TOO BERESII MAA TUN IWA RE SE DIE DIE.
IKAGBE
OGBETURUPON
-JIGBINNI
LI O DIFA F’ESIN O DIFA F’ERANLA
WON NIKI ERANLA WA RUBO KI IWA RE MA BAAR’EHIN
SIT’ESIN
OKO META ATI EGBETALELOGBON OWO NI EBO
ERANLA GBO EBO KO MA RU O
ESIN GBO EBO O RUU
ERANLA LI O TIJE EGBON ESIN TELE RI
ESU WA SO FUN ENIYAN PE KIWON FA ESIN MORA NITORI
ENITI ORUBO NIESU NGBE.
ORIN IFA NAA:JIGBINNIN O O WA L’ORUN ESIN-JIGBINNI O WA
L’ORUN ESIN.
-OGBETUNMOPON-SUNMOSI,BI-OMO-BA-NKE-IYA-RE-
NIAAGBEFUN
LI O DIFA F’ALAWORO-ORISA
TI KOR’OMOGBEPON TIO NBA IGUN KIRI
WON NIKI O RU
ASO FUNFUN KAN BAYI TIOWA LORI
ORISA L’EBO
EGBERINDILOGUN OWO ATI ABO ADIYE MEJI
O GBO O RU.
OTURUPONGBE
-DO’NIDONI-O-GBODO F’ORI-OKO-BA-INA,OSORO.O.GBODOYI-
WO’NU-EGUN-SORO,O JOPURUTUPARATANIILEMOKURO-
L’ALEDE O DAA F’ OMO ILE OLOFIN ATAKITI-GBA-
EGBEWA.WON NI:ORO KAN’DASINU NITORINAA KI O
RU:AKUKO ADIYE MEJI EGBEFA OWO ATI OKUN IJARA LI
EBO.O GBO EBO SUGBON KO RUBO.
IYA OMO NAA LIO LO RUBO NAA NIGBATI ORAN DE BA OMO
RE
ITAN IFA NAA LO BAYI:NI AKOKO NAA OKUNRIN KAN WOLE LO
Y BAOBIRIN OLOFIN SUN. O YA OLOFIN LENU BI LENU BI
ENIKAN TISE LE GBOJU GBOYA WO INU ILE AILOJU TI OUN FI
AWON OBIRIN OUN SI YI LATI LOSE IRU IKA BEE.NITORINAA O
BERE SIIWADI. NIGBATI O WADI ORAN NAA TITI TI OUN KO MO
ENITI O LOSE IRU ISE IKA YI. O PE GBOGBO ILU JO. O GBE
EGBAAWA OWO SILE PELU OBUKO KAN PE:ENIKENI TIOBA LE
TA’ KITI WO’ NU AGBALA OUN YI KIOGBE EGBAAWA OWP TI
OUN FISILE PELU-ERN OBUKO.GBOGBO ILU SEE WON SEE
TI.NIGBANAA NI OMO ILE OLOFIN KAN WA TIOSI TAKITI WO ‘NU
AGBALA NAA.OLOFIN MU OMO NA PE OUN LI ENITI O WO INU
AGBALA OUN LO SIKA YI.ODEE NIGBATI IYA OMO NAA GBO O
YARA SARE LOIRUBO TI OMO RE
KOSILE BI IYA RE TI RU EBO NAA TAN NI ESU WA FI OHUN SI
OMO OLOFIN KAN L’ENU PE:OUN OLOFIN PAAPAA LIOLOBA
OBIRIN RE SUNKINI O LO GBE OMO-OLOMO DESI TIOSI NFEE
PAA OLOFIN WA TU OMOKUNRIN NAA SILE NIKEHIN O SI
GBEEGBAAWA OWO TIOTISE ILERI RE FUNO NAA PELU
OBUKO NAA.
OGBETURA
OTURA-ORIKO
OGBEATE
IRETEOGBE
ATEGBE ,ATEGBE AWO OLOKUN LI ODIFA F’ OLOKUN
AGUTAN ATI EGBAA MESAN OWO LI EBO
WON NI A DI ALAJE A DI OLOMO
O GBO O RU
O DI ALAJE O DI OLOMO ATI BEEBEE
OGBE-SE
OSO-OGBE(OSOMINA)
-ARINNAPERANJE-ESE,OLOGBOF’OSIS’ORUN-O-
NJAREGE,ORUMILA L WON IBA F’ OSISIWAJU KIWON F’
OROS’EHIN KIWON M’EWURE K’EDU
Y WON JE WON KO FUN IGALIYERE JE WON MU WON KO FUN
IGALIYERE MU.
IGALIYERE NFI OSUSU SU WON LOJU
IGALIYERE ORUKO A P’ESU.
ITE-YUE LI ODIFAF’OLOJA-ERU,
WON NIKI O RUBO
OBUKO ATI EGBETAELOGBON OWO KI WON MA BAA FI IBI
SUU.
KO RU BO
OLOJA -ERU ORUKO A PE
O BA WON R’ERU D’OJA WON FI IBI SUU.
OGBEFUN
OFUN ‘GBE
-IGI-RERE,IGI-IGBO,IGI-RERE,IGI-ODAN,
PEREGUN NWANINI AWO ESUMERI
LI O DIFA F OFUN
OFUN NLO NA OGBE PA
WON NIKI OFUN RUBO KI OGBE LE NDE
AGBO KAN LI EBO
O GBO O RU
IFA YI FIHAN NI PE:IJA KAN ATI BEEBEE MBO.
.
.-OFUN NO RA, AJA NO RA
LI O DIFA F OLOBAHUN IJAPA
NLO BAWON N OJA EWELE.
A NIKI O WA RUBO KIOMA BAA GBE S OHUN.
AKOKU ADIYE META,EGBETAELOGBON OWO ATI EDE.O GBO
O RU.
OYEKUNBIWORILODO
IWORI ‘YEKU
OYEKUF’OWORADI
IDIYEKU
-AWO-IRE-IRE-NIIFI-EHIN-TAN’NA LI O DIFA F’
OKUNKUNSU NLO SI OTU-IFE WON NI ORO NIKI O BA WO ILU
NAA LEHIN TI O BA TI RU.
EKU KAN EJA KAN,ABO-ADIYE KAN,KIOFIBO ORI(olusupen) RE
.IFA
NI A RIRE LOHUN PAPOJU.
ITAN IFA NA:
BIOTIDE OTU’FE NI ORU,ESU BERESII KIRI OJULE WON O
NRO-IHIN RE KA PE:BABALAWO KAN WO ILU NISSIYI,KIIDE ILE
ENIYAN KAN IBITI O GBE WA NI WON NTOO SUGBON
OHUNKOHUN TIOBA WON SE AFIN.BEENI BIAFI OJU KAN AN
KO KUN ENIYAN LOJU.BAYI NI ESU SE FUN UN TI GBOGBO ILU
NWO TOO.BEELI O KOO OWO ATI ORO PUPO BOWA ILE RE.
OYEKU’ROSU
-AJAWESOLA,ATE-IYE-IROSU-SE-OLA
LI O DIFA FUN GBEREFU TIISE AREMO ORUMILAWON NI IKIN
RE NIYOO GBE E LA,
WON NIKI O RU:EKU,EJA ATI EWURE
O GBO ORU
IROSO TAKELEKU
Odu IROSU TAKELEKU spearks of envy and seduction and calls for
sacrifices to avoid dire consequences.
WESTERN OBSERVATION:A change of jobs will bring
improvement.
-ITAKUTALI-AITA-ASO,IRIKURIKI.AIRI-OFI
LI O DIFA F’ORUMILA NRE ‘LE OLOKUN-SANDE
WON NIILE OLOKUN NAA A SAN AN PUPOPUPOJU.
NITORINAA KI O RU
EYELE MERIN,AKEREGBE IYE-IROSU ATI
EGBERINLELEGBAARIN OWO NITORIPE NIGBA O BA J’ERU TITI
ARA A LA WON.O RUBO.WON NI KI O TUN RU OBUKO META
ATI EGBETALELOGBON OWO SII.
O GBO O RU
NIGBATI O J’ERU TITI ARA LA WON
O NKORIN BAYI
AWO RE’LE LO F IYE WA O
IYE AWO KO DE KU
IYE AWO KO DE KU
AWO RE’LE LO F’IYE WA O
IYE AWO KO DE KU.
Itakutali-aita-aso,Itakurili -airi-ofi
divined ifa for orumila,who was going to the house of olokun-sannde
He was told that olokun-sande’s house would be very auspicious for
him;
therefore he should sacrifice
four pigeons a gourdful of iye-irosu and eighty-eight hundred
cowries.
becuase he would be envied when collecting his fees
He offered the sacrifice.
He was asked to sacrifice further three he-goats and sixti-six hundred
cowries.
He heard and performed the sacrifice.He was envied when he
collected his fees.
He sang the following song:
awon is going home to replenish his iye powder.
awo’s iye powder has run out.
awo’s iye powder has run out.
awo is going home to replenish his iye powder.
awo’s iye powder has run out.
OYEKU WONRIN
-JAFIRIJARI,KEMKEJAKE,AGADAGIDIWONU-ODO-EF’ARABO-
OMI
LI O DIFA F’ODE.O DIFA F’ORUMILA
ODE NRE IGBO OLIKOROBOJO.
WON NIKI O RUBO KIOMA BAA KUS’OHUN.
AKUKO ADIYE MEJE ATIEGBAAJE OWO.
ODE RUBO
OWONRIN YEKU
SIPISIPÍ-LI-A-NRI’GBA-AJE,DUGBEDUGBE-LI-A-NLU-A-GBEE-
YEBA,
A KILU AGBEE YEBA KIOMADUN KEREDUDU KEREDUDU:A
DIFA F’ORISA-NLA NITORI YEMOWO TIISE IYAWO RE TI NLOS’
OKO LO D’ OKO. NJE ITORIPE KIOMA BAAFI OKO-DIDO PA
OMO-ORISA. A NIKI O RU.
EYELE MERIN,EGBAARIN OWO,ATI IGBIN MERIN.
O RUBO.
IFA YI KANNA LI O DA FUN AJANAA-WEREPE TIISE ALE
YEMOWO. A NIKI O RU .OBUKO META ATI EGBETAELOGBON
OWO KI OUN MA BAA KU.
OYEKUNBARA
OBARA YEKU
-ISIN-NIIF’ ORI-GBOGBO-IS’ADE,OGBO-OPE-NII-F’ORUN-I-
S’ARON
WON SE IFA F’ORUMILA.NIGBATI WON KO SIN IN MO
EKU-AWOSIN MEWA,EWE(IRE) ATI OSE NI EBO.
O GBO O RU.
BABALAWO GUN WON PO FUN UN KIOMA FIWE.
OYEKUN-EGUNTAN
-ENI L’OJA EWON OLA L’OJA OWE
LI O DIFA F’OYEKU TII WON NFI OJO IKU RE DA PIRITI (ojo
merin)
WON NIKI O RU
AGBO KAN
OGBO O RU
OJO TI WON NDA KOIPE
IMO IKU AWO KOIJO’RA.
OGUNDA’YEKU
POROKIPOROKI MO LE HUN’SO
KEKEKE MO LE R’ERU
MO TA MO JERE
IDI ENI LI AIWO BIOTI L’SRO SI,
O SE IFA FUN TETEREGUN
NIGBATI YOO PON OMI ORO KO OLOKUN.
A NIKI O RU.
ORI,IGBIN MEJI ATI EGBAJO OWO
TETREGUN GBO O RU
O PON OMI LO FUN OLOKUN
OLOKUN NI:IWO TETREGUN TO ABARIWON A RO E
LORUN,ASO KONIIWON E.I OUN A MAA MI SII
ORIN IFA NAA:TETEREGUN S’ OLA O PON MI ORO KO OLOKUN
ATIBEEBEE.
POROKIPOROKI MO LE HUN’SO
KEKEKE MO LE R’ERU,
MO TA MO JERE,
IDI ENI LI AIWO BIOTI L’ARO SI.
-EKIKAN-ILE-ABARAGBARADODOGBARADODO
A DIFA F’ENU-ONA-ILE.ARIN-KERE-KAN’BI
WON NIKI O RUBO.
ENIYAN KO NIIWON ON.
EYELE MEERIN ATI EGBERINDILOGUN OWO
O GBO O RU.
OYEKU GASA
ILE-EW-AB’OJUSOKOTO
LI O DIFA FUN WON L’OGERE-EGBE.
A NIKI WON WA RUBO KIWON MA BAA TA’HUN I’AYE
IGBA IREGBE-OGURO,EYELE MERIN,EGBERIN OWO.WON KO
WON KO RU.
OSA YEKU
-OSAYEKU:ISAKUSA-ISAKUYA NIIMUNIIYE’KUN
A DIFA F’EKA-IGI
A NIKI EKA.IGI WA RUBO KI O LE NI ISIMI LOJO IJI
A NIKI WON RU OBAWUN,EYELE ATI EGBEWA OWO
KO RU U.
OYEKUBEKA
IKA YEKU
-AKUSABA-IYANDA,AWOONIMERI-APALA LI O DIFA ONIMERI-
APALA NIGBATI OUN MI RIN-RINAGAN NIGBI OJILEGBEJE
OBIRIN LO TITI O KU OKANSOSO.A NIKI O RU ADIYE
MERINDILOGUN EYELE MERINDILOGUN.ILE ALADIN ATI EWE
IFA (LOFI OSE EGBEFA KO EE RA ILE ALADIN KIOSI BU DIE
LARA ILE ALADIN PAAPAA KIOWA GUN UN POMO EWE
OLUSESAJU SAWEREPEPE ATI ORIJI KO OSE NAA SINU IGBA
ADEMU DARADARA TITUN KIO PA ABO-ADIYE KANKIO DA EJE
RESII FUN WIWE) KI GBOGBO AWON OBIRIN RE TIOTILO LE
PADA BOWA SODO RE.KIWON MAA LOYUN.KI WON MAA
BIMO.O GBO O RU.WON SE EWE IFA TI A WI LOKE FUN UN KIO
MAA FIWE.
LAIPE OBIRIN KAN TIOWA PELU RE LOYUN, O BIMO AWON TI O
TI LO SI TUN PADAWA SILE ONIMERI NIGBATI WON GBO IRO
RERE YI.AWON NAA LOYUN WON SI TUN NBIMO NIBE.
OYEKUN BATUTU
OTURUPON YEKU
OYEKU BATUYE
-IYAN.BI-ATUNGUN,OBE-BI-ATUNSE, OKELEGBONGBO-DI-
ATUNBU-BAALE
WON DIFA F’ONI-ALAKAN-ESURU
NIGBATI O MAA RIRE AYA MEJI LOOJO NIGBATI O MAA RIRE
AYA MEJILOOJO
WON NIKI O RU:AGBEBO-ADIYE MEJI ATI EGBAAJO OWO
OGBO O RU.
OTURA-AIKU
OYEKU-IRETE
-AFINJUYELE,OKUNRUN-KOJEKEWAFUYI,
AWOWONSAN AWO WON NI’ LE KUSERU LI O DIFA FUN
KUSERU.WON NI OMOKUNRIN KAN WA NI’ILE RE.O TI TEERE
RI ARUN KAN KOLUU.O KUN OLWO O KUN LESE OJU ATI IMU.A
NIKI O WA RUBO .IFA A WOOSAN.EBO:EYELE MERIN,EGBAA
MEJILELOGUN OWO ATI EWE IFA (BU OMI SI EE PO-IGI-
AYE,EWE ASUNRUN OPOLOPO IYO ATA WEERE PUPA
DIE.KIOSE WON PO NINU IKOKO FUN WIWE ATI MIMU)
IRETE YEKU
OYEKU-ISE
OYEKU FUN
IWORI WO’ DI
IDI WORI
IWORI ROSU
IROSU WORI
-BIAJE ADUN TITI LAIJE IKORO DIE SII AYE A MAA SU NIIJE
ENITI KO JE IPONJU RI KOMO ADUN ORO. A DAA FUN AWON TI
WNWIPE:GBOGBO IGBA AYE IBA JE KIKI OJO AYE IBA DUN-
ADUNTAN.WON NI AWON A RUBO KI BARA AGBONNIREGUN
JOWO YE GBA WON.ORUMILA NIKI E WA RUBO NITORI WERE
YIN ATI PE KI AYE LE MAAWA BI OODUA TIDA AYE SI IGBA-OJO
ATI IGBA-ERUN KIOMA TASE.EBO:EWURE MERIN,EGBAARIN
OWO ATI BEEBEE.WON KO RUBO.ORUMILA WA JEKI OJO RO
PUPO LI ODUN NAA TITI A KO FIRI OORUN RARA.ENIYAN
BERESII S’OKUNRUN.WON SI KU PUPO NINU ODUN
NAA,OHUN-OGBIN ATI BEEBEE KO DARA. WON PADA WA
RUBO PELU EBE ORUMILA NI:ERU GOKE.O DI
MEJOMEJO,EWURE DI MEJO ATI EGBAAJO OWO.
IWORI WONRIN
IWORI WONRIN
OWONRIN WORI
Yams were dear,palm oil was dear,corn and other foods were dear.
IFA DIVINATION WAS PERFOMED AT IWORI.
iT WAS OBSERVED THAT ALL FOOD ITEMS WERE EXPENSIVE.
They were advised to ofter sacrifice so that food iterms could
become inexpensive.
The sacridfice:two hundred hoes,two hundred cutlasses,tats,
tishes,and twenty yhousand cowries,
They heard and performed.sacrifice.
The babalawo said all the men should take up their hoes and
cutlasses and go work on the farm so that food items could become
inexpensive.
Only hard work can lessen indigence.
Were-nse-eleyaka’de -won-nrerin
divined ifa for ojuogbebikan
who wa advised to sacrifice to preent his wife from beconming
mad,to regain hersanity.
The sacrifice:four snails,eight thousand cowries,and ifa medicine.
IWORI’BARA
--IWORIBARABARA,IWORIBARABARA
A DIFA F’OLE A BU OPURO
A NIKI WON WA RUBO KI WON SIWO NINU IWA TIKO SUNWON.
KI ORAN BARABARA MA BAWON
EBO:OPOLOPO OBI ,EPO EGBAA MEJILELOGUN OWO,EYELE
ATI BEEBEE.KIA MAA FI OWO TORE KIA MAA FI OBI TORE
WON KO WON KO RU.
OBARA WORI
IWORI-OKANRAN
OKANRAN IWORI
IWORI-EGUNTAN
OGUNDA WORI
-WERE-NY’OBE WERE-NYO-ELE,WERE-NSORO-TI-KO-SUN-
WON-S’ETI-AYE,O-NLEWON-KIRI
AOFEWERE,OGUN DA WERE
KINI AO TI S’OGUN
EJEKI A RE’LE ORUMILA LO BERE WO
A DE ‘LE ORUMILA.O GBE IFA SILE WO.
ORI OGUNDA-WORI
ORUMILA Y OGUNDA WORI Y EMIWO NI.I EMIWO KIIJA ESO
IROKO
EMIWO MA KUN INU AYE,EMIWO GBOGBO
OTOOTO,KOS’OHUN TI O DUN BII
K’ALAJ’ EMIWO.
KI A LAGBARA BI OGUN KI A GBON BI IFA.
IFA NIKI E MU WERE WA WO WERE A SAN O.
EBO:IGBIN,EWURE,EGBAA MESAN OWO ATI EWE IFA.
IWORI-OSA
-ENI A SA OLA A SA
A DIFA F’OBAHUN IJAPA
S’ORAN TI KO SUNWON O NSALO SINU IGBO.
WON NI: OJO TI OWO BA TE IJAPA DIDE NI WON MAA DEE
I’OKUN BOWALE
KI O WA SEBO KIWO MA LE DEE I’OKUN LATI OKO BOWALE.
EBO:EYELE,EGBERINDILOGUN,OWO ATI EWE IFA.
O GBO KORU.
OSA WORI
IWORI-OKA
IKA ‘ WORI
-SERARE-SERARE
ENITI O DA EERU LI EERU Y TO
SERARE-SERARE
SIKASIKA FI IDAJI SE ‘RARE
A DIFA FUN INUKOGUN NGBERO IBI WON NI OHUN BURUKU
TIOMA SEYI
YOO DEHIN BOWA BAAJE
A NIKI O WA RUBO
KIO KO IWA-IKA SILE
EYELE MEJI,EGBEJILELOGUN OWO ATI EWE
IFA LI EBO.
-OKAKARAKA-AF’OWO-TI-IKU
A DIFA FUN IKA
IKA NWO OLOKUNRUN KAN NINU ILE,OLOKUNRUN NAA YOO
KU
KI IKA RUBO KI ARUN NAA MA LE RAN ELOMIRAN NINU ILE
EWURE,ADIYE,OTI-OYINBO
ATI EWE IFA (lo ewe laubosa sinu epo ki won maa fi pa’ra)
IWORI’TURUPON
OTURUPON’ WORI
IWORI WOTURA
IWORI-ATE
-IWORI-TEJUMO ‘HUN-TIISE’NI
BI O BA TE’FA TAN KIOTUN IYE RE TE
IWORI-TEJUMO’HUN-TIISE ‘NI
AWO MAMAFI EJA-IGBA GUN OPE.
IWORI-TEJUMO ‘HUN TIISE’NI
AWO MAMAFI AIMOWE WO OMI IWORI.TEJUMO ‘HUN TIISE ‘NI
AWO MAMAFI IBINU YO OBE
IWORI.TEJUMO ‘HUN-TIISE’NI
AWO MAMASAN BANTE AWO
IWORI-TEJUMO ‘HUN-TIISE’NI
A NIKI WON RU:EJA,EGBERINDILOGUN OWO
ATI EWE IFA (fi eja-aro se ewe eso i’obe fun un je)
IWORI-OSE
-TEMI-A-SE-RIWO:
A DIFA F’ OSE A BUFUN IWORI
ENITI O BA DARISO APA,APA-A-PAA
ENITI O BA DARISO IROKO A KOO LONA.
WON NI:OSE WORI A DI ENI-NLA,A SEGUN ODI A REHIN OTA.
KI WON RU:
AGBO IGBA OKO,OGBONKANLA OWO ATI EWE IFA
(lo ako-okuta pomo ataare fun fi fo komu)
O GBO O RU.
IWORI-OFUN
OFUN WORI
IDI-ROSU
IROSU’DI
IDI OWONRIN
OWONRIN DI
OBARA ‘DI
IDI-OKANRAN
IDIKONRANDIKONRAN,IDIKONRANDIKONRAN-IDI-ISU LI O DIFA
F’OLE MEJI NLO OKO-AWO A NIKI WON WA RUBO KIAMA BAA
FIKANRINKAN
ISU DI WON BO LATI OKO WA SILE.ILE NIIBA OLOHUN M’OLE
OWO-ETE MA I’OLE O WON NI:KIL’EBO A NI
:IGBINMERIN,EGBERINDILOGUN OWO ATI EWE IFA (gbo ewe
eso ati olusesaju pelu omi fun fifiwe:kiomaafi igbin se ewe eso i’obe
je)
WON KO WON KO RU .A DE WON BO OKO NITOOTO.WON
NKE:NBAMO MAASEBO IDIKONRAN-DI-ISU.
OKANRAN-DI
IDI-OGUNDA
ORUMILA Y IDI-OGUN-DA
MO NI IDI-OGUN-DA ORUMILA Y BI IDI OGUN TI DARA YI KIOWA
RUBO KI ORI RE LE DARA PELU.
AGUTAN EYELE EGBAA MEJIELOGUN OWO ATI EWE IFA.
OGUN GBO O RU
ORI OGUN DARA.IDI OGUN DARA.
ORUMILA Y IDI OGUN DA,
MI IDI OGUN DA.
A DE LE OGUN A KOB’ENIKAN,MO NI EETIRI ILE OGUN TIAKOB
ENIKAN
GBOGBO ILE DA KESEKESE,
WON NI :IWA OGUN KO SUNWON,NJE BIABIWIPE KI ILE OGUN
KUN SOMUSOMU EBO NI KIASE
EWURE,EGBAAWA OWO AATI EWE IFA.
OGUNDA’DI
IDI’SA
OSA DI
IDI’KA
IKA’DI
-BIABA.RO-LI-AROJU,LAISE-LAIRO-BI-OMINU-NKO’NI,IYA
KIIGBAIJE’ NI A DIFA FUN KODUNMI-AGBA WON NIKI O WA
RUBO KI IYA MA BAA JEE I’AYE EYIN-ADIYE MEWA ORI EDUN-
AARA,EGBAA MEJILELOGUN OWO ATI EWE IFA (loewe oriji ewe
olusesaju ati iyere kiofi eyin-adiye kan see li obe.fi edun-aara sinu
obe yi nigbati o ba soo kale kioji jee li ooro-kutu)AGBA GBO KO RU.
IDI-OTURUPON
OTURUPON’DI
IDI-OTURA
OTURA DI
-ARIBA ABIDIYOO:
A DIFA F’ ORI-AWO TIISE OMO WON LODE OMUKO-EGI.
WON NI:A FI ORI E ADE BABA RE NITORINAA KIOFI AGUTAN
S’EBO
EMIGIGUN.
IDI-IRETE
-IJOKO-AGBA-BIIK’ENI-MA-DIDE-MO.AGBA-M-’OPA-I’OWO.
A DIFA F’OLO.
A NI IBITI OLO JOKO SI KONIIWUU KI O DIDE MO.
A NIKI O RU.EYELE MEJI,EGBEJIELOGUN OWO ATI EWE
GBEGBE.
O GBO O RU.
WON NI:OLO MAAR’ENI GBE OUN.
IDI-OSE
OSE’ DI
OFUN’ DI
IROSU’WONRIN
OWORIN ‘ROSU
-ERINMUYE AWO IRE:A DIFA F’OLAWUNMI NIGBI OLAWUNMI
SUN TIOLA ALA OJUMO MO O NIKI A PE BABALWO WA WO IFA
F’OUN A LO PE ERINMUYE AWO IRE,O DE.ADA’FA LIA RI
OWONRIN’ROSU.O WO TITI O NI OLAWUNMI SISUN LI O SUN
TIOLA ALA LORU NITORI EYI LIOSE PE BABALAWO.LOJU ALA O
NGBO IRO AGOGO-IJO ENIKAN NRERIN SI O .ALA TIOLA IRE
NI.NITORINAA KI O RUBO:EYELE MEJI ADIYE MEJI.EGBIRIN OBI
MEJI EGBEJILA OWO.O GBO O RU. A FI EYELE BO ORI FUN
UN.WON NI :IWO OLAWUNMI KO NI GBAI LLA.
IROSU-OBARA
OBARA -IROSU
IROSU ‘KANRAN
-OLUKONRAN-IWOSI.OLUKOYA-IWOSI
ENITI KO LE KOYA IWOSI,IYA KIIYEWON Y JE:
ADAA F’OLOGBO OMO- AWO
OLOGBO Y OUN MAASEGUN ODI OUN MAA RI EHIN OTA.
A NIKI O WA RU:OBE ATAARE,OGBOKANLA OWO ATI EWE IFA.
OKANRA ‘ROSU
-ORAN-KIIBA’NIKIAYE-ORI,ENIBARI-ORAN-HEEPA-
ONADA,ONANIYI-ADUROTIWON.
A DIFA F’ ADIYE A BU F’AWON OMO ADIYE NIGBATI WON MAA
KIRI DE’GBO EWON.
A NIKI WON WA RUBO BI WON TI NFE LATI MAA RIN KIRI YI
KIWON MAABAA SEGBE SIDI IDADURO.
EBO :OSU,EKU,EJA.EGBERINLA OWO ATI EWE IFA.
-IMORAN-SE-IBIKOSUNWON,ENITI-NSE-IBI-BIOBABEBE
ORAN,ORAN-A-TAN GBOGBO AYE NI NFI ORI JI
MEMO,IMORAN-SE-IBI-KOSUNWON:A DIFA F’OS’ORAN-S’ AKIN
MEBELUFE.GBOGBO WON NI NFI EJO RESUN,BIOBA BEBE-
ORAN WON A NI:O TAN.O WA DI IJO KAN.WON NI:OSO,AJE ATI
ESU BABA WON DI’RE MO ODO OLORDUMARE. NITORINAA KI
O WA RUBO.EYELE MERIN,AGUTAN OBI, EGBERINDILOGUN
OWO ATI EWE IFA(gun ewe olusesaju,oriji ati ose po fun wiwe).O
RUBO WON NI:OLODUMARE A SO FUN ESU KI WON FI ORI JII.
IROSU-EGUNTAN
OSA’ROSU
-KEKEPARERE,OSA ‘ROSU
AYE-I-KELE NI IGBIN WA,
OSA ROSU A DIFA F’ ALAGEMO.
WON NIKI ALAGEMO MAA FI ESO ESO SE AYE,.
AYE ALAGEMO A TUTU
WON NIKI O RU
EPO ORI EJA-ARO NLA ATI EGBAASAN OWO.
O RU U.
IROSU’KA IRO-AGOGO-AGBOKA
A DIFA F’ORUMILA
WON NI NIBI GBOGBO AYIKA AYE NI WON MAA GBO ORUKO
RE TI WON SI MAA A MOO.
WON NIKI O RUBO KI ARA LE ROO
EBO:EJA-ARO,EYELE EGBAAWA OWO
O GBO ORU.
IKA’ROSU
IROSU’TURUPON
OTURUPON’ROSU
-OTURUPON’ROSU,ARIWO NI:
A DIFA FUN DELUMO
WON NI OKO KONIIJE KI AYA KO SIMI
NITORINAA BII DELMO BA RUBO OKO RE A JEKI O SIMI.
IGBIN MEJI ATI EGBEELOGUN OWO
O GBO O RU
WON NI :IGBIN MEJI KIIJO ‘RAWON LENU.
IROSU ‘TURA
-ENIBURUKU-NI-OJOTI-A-NYIN-WON:A DIFA F’OLODUMARE
WON NIKI O RUBO KI ENITI O MAA RAN NISE YI MA LE KO ISE
NAA.KI AYE LE MAA GUN.IJAPA MEJI EWE OGBO ATI
EGBETALELOGBON OWO.O GBO O RU .WON BO ORUN
RE,NIGBATI O RUBO TAN,O WA RAN IROSUTURA LOSI ODE-
AYE.AWON ARAYE NIIWA IROSUTURA KO SUN WON.ODUDUA
NI:IRE NI OUN FISE D’AYE.NITORINAA OUN KO JE FI ELOMIRAN
RO’PO RE.O NI:BI EGBE BA JO BOBAJE WON A TUKA.BI OJA
BA KUN BOBA-PE TITI A TU.BIIBATIRI BI OMO-ENIYAN BA JO
TITI TII WON KO BA LE TUKA LO ILE WON.
OTURA-IROSU
IROSU-ATE
IRETE’ROSU
IROSU-OSE
OSE-ROSU
-OBIYENMEYENME
ADIFA FUN TAKOTABO DIYE
WON NI ADIYE A MAA ABIYAMO KI WON RUBO
EWURE ATI EGBAAWA OWO
WON GBO WON RU.
IROSU’FUN
-IROSU’FUN:IRO EJI AGBOKA
A DIFA F’ EKUN WON NIKI ORUBO KIOMARI IJA SOPONNA.
EBO:OPOLOPO EPO NINU AGBADA OKA TI A DIN,EKO TI OMI
FO SINU IGBA.
EKUN GBO O RUBO SUGBON KO RUBO PE.
O NI :KO DAJU BI OKUNRIN KAN WA TIOLE TE OUNLOJO IJA.
WON NI:SOPONNA A BAA JA SUGBON KO LE PAA.
OFUN’ROSU
OWONRIN’BARA
-O MI RI MI ,ME RII
OWONRIN ‘BARA;A DIFA FUN OWA WON NI:
OHUN TI A NWAMBE NITOSI ENI AFAIMO
WON NIKI A RUBO KI BARA AGBONNIREGUN LE FIHAN NI
ORUMILA LERIN IPIN,IBIKEJI OLODUMARE:
O NI OHUN TI A NWA NBE NITOSI ENI AFAIMO
EBO:AGBEBO -ADIYE,EGBAAWA OWO ATI EWE IFA (ori
awonriwon meji)
O GBO ORU
WON NI :TO ABATIWON,OOWA A MAA RI OHUN TI NWA O.
OBARA ‘WONRIN
-KIL’ALEMO-EYISI
AYO-LIALEMO-EYISI
A DA F’ORUMILA ALADE NBE LAARIN IPONJU
WON NI:ODUN ORO DE
EYELE IYO ATI EGBEWA OWO LI EBO
O GBO O RU.
OWONRIN’KONRAN
-OJO KAN MBE OJO-ERIN OJO MIRAN MBE OJO EKUN.A NI
EWO NI A KAN YI WON NI:OJO IBANUJE,A DAA F’OBAHUN
IJAPA AF’ ORAN-BI-EKUN-S’ERIN.WON NI ONI OJO
EDUNRUNMO NITORINAA KI O RUBO EFUN,OSUN,EYELE EWE
OWU ATI OGBOKANLA OWO O GBO KO RUBO.O NI KOS
ORANIBANUJE TIO LE KAN OUN LI AYE KI OUN MAFISE ERIN
RIN.O WA RUBO NIKEHIN NIGBATI EDUNRUNMO PAPOJU.
NITORINAA KIWON TOOSE EWE IFA FUN UN,WON NI: ERU
GOKE.O GBO O RU WON SE EWE IFA FUN UN EYIINI NI NIPA
GIGUN AWON EWE TI A DARUKO LOKE PELU OSE KIOMA
FIWE.
-OJO KAN MBE OJO ERIN OJO KAM MBE OJO EKUN
A DAA F’EGASESE EYE ORI OWU.
O NI:EWO LI EYI
WON NI:OJO ATI OJO ERE ,A NIKI O RUBO
EYELE,IGBA-IYAN,AWO-OBE,EMU ATI EGBERINDILOGUN OWO.
O GBO ORU.
OKANRAN’WONRIN
OGUNDA WONRIN
OSAWONRIN
OWONRIN’KA
IKA’WONRIN
OTURUPON -OWONRIN
OWONRIN -OTURA
-IJAMJA KO TURASILE LEEKAN.A DIFA FUN IGBIN OMESO NLO
B’ EKUN JIJA OJIJI
WON NI:EKUN W NI IMURATELE NIGBGBOGBO KI IGBIN MASE
ENITI A KOLEMU OLORUN LIAA FUN.
WON NIKI O WA RUBO KI IPIN LE JA FUN UN
EBO:ABAHUN-IJAPA,EGBERINDILOGUN OWO.
O RUBO.
-A WAA-WAA :A RII
A DIFA FUN EWE-GBEGBE,WON NIKI O WA RUBO KIOBA LER
OHUN RERE GBEKELE
EBO:OROGBO MERINDILOGUN EGBAA MEJILELOGUN OWO
O GBO O RU.
WON NI :IKU KONIIPA GBEBE ARUN KONIIDEE GUN ‘LE ARA
YOO MATUU TOJOTERUN.
OTURA-WONRIN
OWONRIN-IRETE
IRETE WONRIN
OWONRIN-SE
OSE-OWONRIN
OSE.ONIWO,OSE-OLOOGUN
OWONRIN FU
OFUN-WONRIN
OBARAKANRAN
-OBARAKANRAN LI O DIFA F’EYE-IWO
WON NIKI O WA RUBO KIOMALE S’ORAN TI AWON EYE-OKO
MAA FI MAA BINUSII.
EBO:OKA (agbabo)ATAARE ATI EGBEWA OWO.
O GO O NI. OUN KO MAA RUBO.
-O NFEWI-KOLEEWI,OBARAKANRAN KOJE.ENITIMOSE O
NFEFOKOLEEFO,OBARAKANRAN KOJEKI O RO JO MI FUN
AYEGBO
IGI-EKU NIIKI’RAN M’EKUNINU.IGI-EJA NIIKI’RAN EJANIMU
ELEMBERUN KIIWI TI ENU RE F’AYE GBO.EWE IFA:IGITIAFISIN
EKU IGI TIAFISIN EJA,KOLAWE KAN ATI EWE
ELEMBERUN.KIAKOWON JO SINU OWU GBEREWU,KIAFI OWU
DUDU ATI FUNFUN DI WON PO KIOLE
DANYINDANYIN.KIOMAAWA NINU APO-EWU.KI A MAA JE
ATAARE MESAN FI WUSA RE.
OKANRAN-BARA
OBARA-OGUNDA
OGUNDA-BARA
OBARA-OSA
-OBARA-OSA:A DIFA F ETA ,WON NI OKAN NINU AWON TI O
NRA OJA LOWO RE NFEE SALO KIOLEJE OWO RE GUN
NITORINAA KIO-WA RUBO KIOLE MAA RI AWON ONIBARA RE
KI OWO LE MAA WUWON ON SAN FUN UN:EYELE ,AGBEBO-
ADIYE,OGBOKANLA OWO ATI EWE IFA (gun ewe eesin,ewe tagiri
ati ose po pa adiye sii kiomaa fiwe)
O GBO O RU.
WON S’EWE IFA FUN UN.WON NI:IJO TI EESIN BA SIN OWO RE
NIIGBAA.
OSA-BARA
-OSABOWARA,BIOBASALO KIIPEDE
(lagbaja)SEKIOBOWARA.WARAWARA LI OMODE Y BO OKO
EESIN (lagbaja) SEKI OBOWARA .EWE IFA: AO PA OBI (iwarefa)
ALAWE MEFA,EWE EESIN(funfun) WARA MEFA.AO TE IYE-
IROSU NI ODU OSA-BARA NINU OPON-IFA KIAPEE BIATIWI
LOKE ATI ORUKO ENINAA TI O SALO,AO MAA BU IYE-IROSU
NAA SINU EWE EESIN ATI AWE OBI KAN KIAMA GBEE LO SIDI
ESU NIGBAMGBA ITA TABI LIOMA NI ENUBODE ILU.BAYI LI
AOSE
TI AOFI RIN NIGBA MEFA LO SIDI ESU.EYI LIATI NPE AISA
BOWALE OHUN IYANU TIOWA NIBE NIIPE BIATINPEE OUN YOO
MAAGBO OHUN WA NI ETI RE.EWE EESIN KAN ATIAWE OBI
KAN TITI YOO TI TAN.KI A TA EPO SORI ESU BIABA TI SETAN.
OBARA-KA
OBARATURUPON
OTURUPON’BARA
OBARA -TURA
-APAPAITAKO,ATUWON-NILETUWON-LOKO,
A DIFA FUN ONILE-ADIYE ATI AWON OMO RE
WON NI OTA TI O LAGBARA JU WON NBOWA BAWON,BIEBASA
KURO NI’LE LOS’OKO IYOO TUN WA BA YIN L’OKO SUGBON
BIEBA SEBO EO YE OWO A JE FUN YIN.
EBO:IGBIN EGBERINDILOGUN OWO ATI EWE IFA (ewe owo ati
igbin sise l’obe kiajee)ONILE-ADIYE DIE RUBO
WON NI ‘’AWODI KOLERI F’IGBIN SE:AWODI WO IGBIN KORO.
OTURA-BARA
OBARA RETE
IRETE-BARA
-
ASEJEJESAJE,ASEJEJESAJE,ASEJEJESAJE,WARAWARAMASE
WARAWARAMASE,WARAWARAMASE IRETE-OBARA KIOMU
IRE UWA BA EWE IFA:SE EWE TETE-ATETEDAYE L’OBE JIJE
NIGBAKUUGBA PELU EJA-ARO KIOSI MAA DIGBA LO EWE
WORO ATI IYERE,KIOFI EJA-ARO SEE LI OBE FUN
JIJE.BIOBATUTU KI O TE IYE-IROSU NI ODU IRETE-OBARA
KIOBE OHUN RE SIIGEGEBI A TI PEE LOKE YI,KIODAASINU
OBE NAA KI OMO TI IWA RE BA LE PUPO JEE
OBARA-OSE
OSE-BARA
OBARA-OFUN
OFUN BARA
OKANRAN-EGUNTAN
OGUNDA-KANRAN
OGUNDA’KAN.OKANRAN KAN,OKANRAN-KANGUN-KANGE
A DIFA FUN EGUNGUN.EGUNGUN NS’OWO AIPE,WON NI ‘LI
ODUN YI LI OUN YOO BO’RI NINU ISE.
WON NI KIOWA RUBO:AGBON OBI ERUU-PASON.
OKANRAN-SA
OSAKANRAN
OKARAN-KA
IKA-KONRAN
OKANRAN TURUPON
OTURUPON KONRAN
-SEMIKI’MISE-O-KIIJEKI-ORAN-O-TAN.
A DIFA FUN OLUKOYA
WON NI ORAN KAN WA LAARIN OUN ATI AWON EBI RE.WON
NIKI O WA RUBO KI ORAN NAA MAA LE BA IREPO JE NINU EBI.
EBO :ADIYE MERIN,EPO,EGBAAJO OWO.
O GBO ORU.
OTURA KONRAN
OKANRAN-ATE
IRETE-OKANRAN
OKANRAN’SE
OSEKONRAN
OKANRAN-OFUN
-OFUN KONRAN
OGUNDA’SA
OSA’OGUNDA
-OSA OGUNDA ‘LE JA,OIDERE AWO IGBADO,OLUKO AWO
IGBADO AIJAGOGOROGO AWO OLIBARA LI O DIFA FUN
OLIBARA.OIDERE AWO IGBADE(alejo) O NI OUN RI IRE AJE FUN
OLIBARA NITORINAA KIORU:EYELE,AGUTAN ATI EGBAA
MEJILELOGUN OWO.O RUBO .ALUKO AWOIGBADO (oun naa
alejo)O NI OUN RI IRE OMO.O NIKI OLIBARA
RU:EWURE,AGBEBO-ADIYE ATI EGBAA MERINDILOGUN
OWO.O GBO O RU.AIJA-GOGOROGO AWO ILE OLIBARA,O NI
OGUN LI OUN RI,O NIKI OLIBARA RUBO:AGBO EGBAA
METALELOGBON OWO . O NI BI OLIBARA KO BA RUBO.O NI
OGUN YOO DE NI OJO MOKANLA.
OLIBARA KO RUBO.OJO MOKANLA PE,OGUN DE OLIBARA
SA’GUN KURO NI ILU.
OGUNDA’KAA
IKA-OGUNDA
-OGUN-DAMIL’ARE
OGUN JOWO GBE MI.
KOS’ENITI O NI EJO TABI IJA TIKIIWIPE,KI OGUN JOWO GBE
OUN
ENI NSE RERE ARI’RE.ENIKAN DANDAN LI OGUN YOO GBE.
A DAAFUN ADETUTU,
OMO -OJOKOF’OKAN-BALEMI(eemi),akude’dajikijatoode.
won niki o ru:aja kan,emu esun-isu ati epo. ogbo ko rubo.
nota parece que el odun 204 no tiene el final ademas hay un salto al
206 y despues al 210
OTURUPON EGUNTAN
IRETE-EGUNTAN
TETE WA TE K’ARA O RO WON
A DIFA FUN PEREGUN
WON NIKI PEREGUN WA RUBO KI ARA LE ROO KIOWA TE IFA
EBO:OGEDE WEERE TIOPON ORI EGBEJILELOGUN OWO .
O GBO O RU .O TE IFA
WON NI:ARA YOO RO PEREGUN TITI AYE:ARA RO PEREGUN.
-IRE-TE-MI-LOWO
A DAA FUN ORUMILA ALADE NDE LAARIN IPONJU WON NIKI O
RUBO ODUN ORO DE
EBO:EYELE ,ADIYE,EDE ATI EGBEWA OWO.
O GBO O RU.
OGUNTAN’SE
OGUNDAKOSE,OGUNDAKORO,EEWO,KIAMASE FI IYA JE
OGUNDA,
A DIFA FUN OLOWO.
WON NIKI O WA RUBO KIOMABAA JIYA LAELAE
EBO:EYELE ,AGUTAN ATI EGBAA MEJILELOGUN OWO.
O GBO OR RU
OWO E JEKI OMO OLOWO KIOMAALOO OWO
OWO IKOKO LIAFIIWO IGI ,OWO ORISA LIAFIIWO AFIN:E FI
OWO MI WO MI.
OSE-EGUNTAN
OGUNDA-FU
OFUN-EGUNTAN
OSA-KA
IKA-SA
-IWABURUKU-NMU’NIIS’OJO
A DIFA FUN OLE
WON NI OLE KOMAA I’AYA BI OLOHUN
WON NIKI OLE WA RUBO KIOBAA LEMAA GBA ONA ESO NI
INKAN
EBO :IGBIN MERIN,EGBAASAN OWO
ATI EWE IFA (lo ewe woro ati eso siseje gegebi obe pelu igbin)
KO RUBO.
OSA-OTURUPON
-KOROMOGBEPON.A DIFA FUN OSA ATINUSOJO
WON NIKI O WA RUBO NITORIPE KIOBAA LE R’ OMO BI
EBO:EWURE,AGBEBO OWO ATI EWE IFA.
O GBO EBO KO RUBO.
-OSA -OTURUPON,OSA-OTURUPON
A DIFA FUN AWO (eran)
WON NI:ARA AWO A LE A PE I’AYE JU ERANKE
RAN
EBO: EYELE,AGUTAN,OBI ATI EGBAA MOKANLELOGUN OWO
O GBO O RU.
OTURUPON -OSA
OTURA-SA
OSA-RETE
IRETE-SA
OSA SE
OSE-SA
OSA-FU
OFUN -SA
IKA-OTURUPON
-AWUN NJOLA IGBA,IRERE F’AYA GBENKEN OGBO AIRA NI Y
SAN IROKO LORI TEWETEWE.A DIFA FUN ONILE OBIRIN KOLE-
KAASE MERINDILOGUN .WON NIKI O RUBO KIOBALE RI
ENIRERE FI EHIN TI ,KI OLE MA LE JI OHUN TIOMAA DUN UN
JU LO.EBO:EYELE MERINDILOGUN PEPEYE MEJI,IGBIN
MEINDILOGUN EGBAA MERINDILOGUN OWO ATI EWE
IFA.ONILE OBIRIN KO KO RU .O NI :KINNI OHUN TI OUN Y BA
MAA WA ALAFEHIN TI SE NIBO LI OLE YOO TI WA JA OUN NINU
YARA MERINDILOGUN OBALUFON FEE O KO OSANYIN FEE O
KO OGUN FEE O KO ORUMILA FEE O KO OBIRIN YII NITORIPE
KI WOW AWON IKA ENIYAN MA BA TE OUN.OBIRIN NAAA MAA
LO SUN NINU YARA KERINDILOGUN A SI TI GBOGBO ILEKUN
ILE NAA LI ALE.NIJO TI ORUMILA MURA TAN TI O NLO DOJUTI
OBIRIN NAA,IROFA OWO RE PELU IGEDE LI ENU RE LIOFI
SI’LEKUN GBOGBO LOBAA.NINU OHUN GBOGBO WONYI TI
ORUMILA SE NINU ILE NAA ATI SI OMOBIRIN NAA,KOSI ENIKAN
TIOJI LOJU OORUN ATI GBOGBO AWONOLUSO ILE
NAA.NIGBATI ILE MO TI OBIRIN NAA JI LOJU OORUN O YE ARA
RE OWO O RI IHUN GBOGBO TIA SE SII I’ARA TI KO SI MO
ENITI O SEE. O BI AWON OLUSO ILE,WON KO LE SO FUN UN
JU PE AWON SUN NI GBOGBO ORU MOJUMO ONI.O WA PASE
PE KI GBOGBO AWONOMO ILE OUN KO AGOGO KI WON BO SI
ODE ILU,BI WON TI NLUAGOGO KI WON MAA SEPE SO ENITI O
WA SILE OUN WA SIKA LORU MOJUMO (ijo naa) ONI.WON WIWI
WON FOFO TITI.WON KO RI ENI DA WON LOHUN.NI KUTUKUTU
OJOKEJI NI ORUMILA TI BOS’ODE PELU AWON MOSUMORE
RE:WON NLU AGOGO WON NKORIN KAAKIRI BAYI PE:EPE A
P’ELEPE AWEREPEPE,EPE A P’ELEPE,AWEREPEPE ATI
BEEBEE.NIGBATI OBIRIN NAA MOPE ORUMILA TIOTIFE OUN TI
LIOYE INKAN YI.O WA RANSE LO BEE ATI PE KI A BA OUN SO
FUN UN PE:ORUMILA LI O TOOSE OKO OUN NITORINA A KI O
MAA BO NI ILE OUN O ‘’
ITUMO IFA YI:BIABA DAA IFA YI NIGBATI A NGBO’RI TABI
LIAKOKO ESE-NTAYE OMOBIRIN AOSO FUN AWON OBI (baba
ati iya) OMO NAA PE AYA BABALAWO NI OMOBIRIN YI YE
KIOJE,OMO NAA YOO NI OHUN-ELO AYE YI PUPOPUPO.KI O
BAA LE NI ISIMI,BABALAWO NI OKO RE.
OTURUPON -KA
ABIJOLE IRE OKO ANIMO.A DIFA FUN OTU WON NIKI OTU WA
RUBO
AWON AYA RE’ A MAA BIMO NILE ,AWON IGI TI A NKA I’OKO A
MAA SO ESO FUN WON KA
EBO:OGEDE OPOLOPO OBI OPOLOPO OROGBO YANRIN
(erupe) ATI EWE IFA
O GBO O RU.
IKA-OTURA
OTURA KA
IKA-IRETE
IRETE -KA
-IKA -SE
OSE-KA
IKA-FU
OFUN KA
OTURA-TUTU
OTURUPON-RETE
IRETE-TUTU
OTURUPON-SE
OSE-OTURUPON
OTURUPON FUN
OTURA-RETE
IRETE-TURA
-IGEDE
OTURA-SE
OSETURA
IGEDE
-IGEDE
OFUN-TURA
IRETE-SE
-IGEDE NAA:
F’ ORILAKU,F’ ORILAKU,F’ORILAKU.
AGBOGBNIWONRAN.
EKUN AMOMONIBUU,EKUN AMOMONIBUU,EKUN
AMOMONIBUU.
ENITI O BA DUGBOLU EGUN OGAN EGUN OGAN A GUN UN
ENITI O BA DUGBO LU EGUN ESU EGUN ESU,A GUN UN. ENITI
O BA DUBOLU ESU ,ESU A SEE ATI BEEBEE.
EWE IFA NAA:YANGI(okuta)ESU OBE TITUN META TIARO LI
AGBEDE ILE WA ,EEPO IGI IPARA,ONIRUURU PAKUN (itakun)
ELEGUNKIAGEE SI WEWE,KIAKOWO SINU IKOKO AGBO
NAA;KIATEE NI ODUIFA IRU-EKUN,KIAPE IGEDE RE SII
KIAGBAA DASINU IKOKO AGBO NAATIBUTIBU OMI SII,KIADEE
EERU TABI ERUPE TIPO SAN AN TABI LEE FUN OJO MEJE
KIATOOSII.KI A MAA FI AGBO NAA WE;A KOGBO DO MU NINU
RE.
-IJALA,IJALA,IJALA
ALAGERE-IDE,ALAGERE-IDE,ALAGERE-IDE
OWORONIKOKO,OWORONIKOKO,OWORONIKOKO.
ONDESE NI YEYE WON.NIGBI WON MAA RO,WON SORI
GBAKONGBAKON MEJI.OLODUMARE WA PASE Y GBAKON-
GBAKON MEJI KIIJA ARA WON.OMO AWUN KIITO AWUN LEHIN
ATI BEEBEE.OMO IGBIN KI Y TO IGBIN LEHIN ATI BEEBEE.OMO
EJO KIITO EJO LEHIN ATI BEEBEE.IFA OKU KIIRO OMO
ELOMIRAN KI ISASI AWONOLISASI MA LE MU MI ATI BEEBEE.
EWE IFA NAA:OLOBAHUN,IGBIN,EJO IGI IROKO MEJI TI
OD’ERU,KIASA EEPO WON ATI IFA OKU.KIAJOWON PO
KIAAKOO SINU (ato) ADO KAN.KIAMAA BUU DIEDIE NINU RE KI
A MAA TEE NI ODU EKUN-FIIRUNA ‘LE,KIAMAA DAA SINU EPO
KIAMAA LAA.KIAMAA FI NINU RE PA’RA BIA BA FE.ENIYAN DIE
LE BA WA LAA NINU EPO .KIAMAA PE IGEDE RE SI ODU NAA
KIATOO DAASINU EPO FUN LILA.IFA YI JE AROBI FUNGBOGBO
ISASI.
OSE-BI-IRETE-SILE-AJE
IFA Y O DI ALAJUBARAKA.
EMI Y 0 DI ALAJUBARAKA,
BI A BA LO JUBARAKA KI O JUBARAKA
OBI OLOTOORO,O BI OLOTEERE.O BI ONAWOFUNMIRIN.
ONAWOFUNMIRIN LIOBI AJE,
AJE LIOBI ENIYAN AJE DI O R’OKUN,ENIYAN DI O RE IRADA
OSE KIOSAREGEGE RE Y MU AJE WA FUN MI ILE OLOKUN...
IRETE KIOSAREGEGE RE IRADA KIOLOMU ENIYAN FUN MI
WA...APE KIOMAJEKI IRE MI PE KIOTOO DE.
EJIRIN KIOMAJEKI IRE MI RIN JINNA KIOTOO-
DE.BIAGBA’LEGBA’NA ODO ATITAN LI AIKO ORI RE SI.
EWE IFA YI:GUN EWE APE,EWE EJIRIN,ERUPE ILE ATITAN ATI
OSE EGBEFA PO KIOTE ODU OSE-IRETE S’ARA EGBE OGIRI
NINU ILE(yara)EFUN TIAFI OMI PO NIKI A FI TE ODU OSE
KIASIFI OSUN TIAFI OMI PO BAKAN NA TE ODU IRETE.PA
EYELE MEJI TI O DARA,OKAN FUN OSE ATI EKEJI FUN
IRETE.EYITI O SIKUN NINU EJE EYELE MEJEJI NAA KIADAA
POMO OSE TI A GUN NAA;KO OSE NAA FI LE EGBE OGIRI OKE
ODU TIATITE NAA.ILO RE: AO MAA BU OSE NAA FUN WIWE
NIGBAKUUGBA TI AO WE.
IRETE-OFUN
OSEFU
OFUN-SE