Primary One Yoruba-1
Primary One Yoruba-1
APA KINNI
1. Omode okunrin ma n __________ ki agbalagba (a) kunle (b) sare (d) dobale
2. Onka Yoruba “eewa” je ______(a) 10 (b) 2 (d) 4
3. Bawo ni a se n ki ni asan ni ile Yoruba? (a) ekaasan (b) ekaale (d) ekuule
4. Imototo bori _______ (a) arun (b) ara (d) iwe
5. “B” fun _______ (a) baagi (b) ile (d) igo
6. Ojoru je _______ (a) Tuesday (b) Wednesday (d) Friday
7. “F” fun ____ (a) Ike (b) fila (d) baba
8. Ojo abameta je ______ (a) Sunday (b) Saturday (d) Thursday
9. Ki ni oruko oluko re? _______________________________
10. Ojo melo lo WA ninu ose (a) meta (b) meje (d) mewa
APA KEJI
1. Ko alifabeeti A de GB
________, _______.
Apa keta
Taiwo ati Kehinde sese wole si ile – eko ni. Obinrin ni awon mejeji. Won si nife ara won gidigidi,
sugbon ole ni Taiwo, ti o ba di asiko ise nse ni o maa n yose sile fun kehinde. Eyi lo fa ti awon obi
won fi feran kehinde to won si maa n ra nkan fun ju Taiwo lo.