Curaçao
Erekusu Ileagbegbe Curaçao Island Territory of Curaçao Eilandgebied Curaçao Teritorio Insular di Kòrsou | |
---|---|
Orin ìyìn: Himno di Kòrsou | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Willemstad |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Dutch, Papiamentu, English and Spanish |
Ìjọba | See Politics of the Netherlands Antilles |
• Monarch | King Willem-Alexander of the Netherlands |
• Govenor | Lucille George-Wout |
Eugene Rhuggenaath | |
Constitutional monarchy part of the Netherlands Antilles | |
Ìtóbi | |
• Total | 444 km2 (171 sq mi) |
Alábùgbé | |
• 2009 census | 141,766 |
• Ìdìmọ́ra | 319/km2 (826.2/sq mi) (ranked as part of N. A.) |
Owóníná | Netherlands Antillean guilder (ANG) |
Ibi àkókò | UTC-4 (-4) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 599 |
ISO 3166 code | CW |
Internet TLD | .an |
Curaçao (pípè /ˈkjʊərəsaʊ/; Duki: Curaçao, Papiamentu: Kòrsou) je erekusu ni apaguusu Omi-okun Karibeani, nitosi etiomi Venezuela. Erekusu Ileagbegbe Curaçao[1] (Dutch: Eilandgebied Curaçao, Papiamentu: Teritorio Insular di Kòrsou), to lamupo mo erekusu gbangba na ati ereku Klein Curaçao ("Curaçao Kekere"), je ikan ninu awon erekusu ileagbegbe Netherlands Antilles, nipa bayi o je apa kan Ileoba awon Nedalandi. Oluilu re ni Willemstad.
Coordinates: 12°11′N 69°00′W / 12.183°N 69.000°W
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ English name used by government of Curaçao and Government of Netherlands Antilles (English is official language of Netherlands Antilles and Island Territory of Curaçao)