Imule Awon Agba
Imule Awon Agba
Imule Awon Agba
ORI OKETE TO NIRUN, ESO WERENJEJE TOPO, ORI ATI ODINDIN ATAARE KAN.
SISERE:-
AO FI ORI NAA BOO GBOGBO ORI OKETE NAA TIKONI HAN RARA, A OTUN WA FI EESO WERENJEJE NAA
BOO GBOGBO ARA ORI NAA TIKONI HAN, AO WA GBE SINU AGBADA PELU ATARE KAN, AO TA EPO PUPA
YII ARO NAA KA. AO LO TIYIOKUNA LAINI KANLE.
LILORE:-
AO DA EBUYII SINU CUP KAN PELU ODINDIN MILK OLOPE KAN (PEAK MILK), AO WA FI LOO LEKANNA,
LEYIN TI ABALOTAN, AO WA FI OTI SIN INU CUP NAA NU, AO WA GBEMU. AAGO KAN ORU NI AO LO ISE
YII.