Jump to content

Alibéníà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Albáníà)
Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Albáníà
Republic of Albania

Republika e Shqipërisë
Orin ìyìn: [Himni i Flamurit] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
Hymn to the Flag
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green) on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tirana
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaAlbanian1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
92% Albanians,
6% Greeks,[1][2] 2% others[3]
Orúkọ aráàlúAlbanian
ÌjọbaOrílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
• Ààrẹ
Ilir Meta
Edi Rama
Formation
1190
2 March 1444
• Independence from the Ottoman Empire
28 November 1912
2 December 1912
28 November 1998
Ìtóbi
• Total
28,748 km2 (11,100 sq mi) (143rd)
• Omi (%)
4.7
Alábùgbé
• 2010 estimate
3,195,000 [4] (136th)
• 2001 census
3,069,275 [5]
• Ìdìmọ́ra
111.1/km2 (287.7/sq mi) (63)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$23.864 billion[6]
• Per capita
$7,453[6]
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$11.773 billion[6]
• Per capita
$3,677[6]
Gini (2005)26.7[7]
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.719[8]
Error: Invalid HDI value · 64th
OwónínáLek (ALL)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (CEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù355
ISO 3166 codeAL
Internet TLD.al
  1. Greek, Macedonian and other regional languages are government-recognized minority languages.

Alibéníà (Gbígbọ́i /ælˈbniə/ al-BAY-nee-ə, Àdàkọ:Lang-sq, Gheg Albanian: Shqipnia/Shqypnia), lonibise bi Orileominira ilẹ̀ Alibéníà (Àdàkọ:Lang-sq, pipe Àdàkọ:IPA-sq; Gheg Albanian: Republika e Shqipnísë), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani. O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo[a] ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ilaorun ati Girisi ni gusu ati gusuilaorun. O ni eti-omi ni egbe Omi-okun Adriatiki ni iwoorun, ati legbe Omi-okun Ionia ni gusiiworun. O fi iye to din ni 72 km (45 mi) jinna si Italy, nikoja Strait of Otranto to ja Adriatic Sea po mo Ionian Sea. Albáníà je omo egbe UN, NATO, Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe, Igbimo ile Europe, Agbajo Owo Agbaye, Agbajo Ipade Onimale be sini omo egbe lati ibere Isokan fun Mediteraneani. Albania ti fe di omo egbe Isokan Europe lati January 2003, be sini o ti toro lati di omo egbe lati 28 April 2009.[9]

Albáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na.[10] Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.[11][12][13]



  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named IJ
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named JP
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named cia
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named instat2010
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named 2001census
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 "Albania". International Monetary Fund. Retrieved 12 April 2011. 
  7. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 13 May 2009. Retrieved 1 September 2009. 
  8. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  9. "Albania applies for EU membership". BBC News. 28 April 2009. http://news.bbc.co.uk/2/hi/europe/8023127.stm. Retrieved 29 April 2009. 
  10. CIA – The World Factbook Archived 2020-05-15 at the Wayback Machine. Àdàkọ:WebCite
  11. Reports: Poverty Decreases In Albania After Years Of Growth.Dow Jones Newswires, 201-938-5500. Nasdaq.com
  12. Albania plans to build three hydropower plants.People's Daily
  13. Strong GDP growth reduces poverty in Albania-study. Reuters. Forbes.com
pFad - Phonifier reborn

Pfad - The Proxy pFad of © 2024 Garber Painting. All rights reserved.

Note: This service is not intended for secure transactions such as banking, social media, email, or purchasing. Use at your own risk. We assume no liability whatsoever for broken pages.


Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy