ISO 3166-2
Ìrísí
ISO 3166-2 ni apa opagun ISO 3166 to je titejadesiwe latowo International Organization for Standardization lati setumo àwon amioro fun awon oruko awon ipinsabe koko (f.a igberiko, agbegbe tabi ipinle) awon orile-ede ti won je siseniamioro ni ISO 3166-1. Oruko ifisise re ni Awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won - Apa 2: Amioro Ipinlabe Orile-ede. 1998 ni o koko je titejadesiwe.
Idi ISO 3166-2 ni lati fidimule opagun kariaye amioro oniletanomba kukuru ati ayasoto lati soju awon ipin amojuto awon orile-ede.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |