Akojopo Asiri Yoruba PDF

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 1

Akojopo Asiri Yoruba

PDF

Uploaded by Mikkymiczy Oladunjoye on Jun 19, 2020

 88% (90) · 56K views · 448 pages


AI-enhanced title

Document Information 

Date uploaded
Jun 19, 2020

Original Title
AKOJOPO ASIRI YORUBA.pdf

Copyright
© © All Rights Reserved

Available Formats
PDF, TXT or read online from Scribd

Share this document


Facebook

Twitter

LinkedIn

 
Email Copy Link

Did you find this document useful?

 88%  12%

Is this content inappropriate? Report this Document

Download now 

AKOJOPO ASIRI YORUBA


alternanthera nodiflora – Dagunro
Butryospermum paradoxum – Shea tree – Ori
Allium sativum -Garlic – Ayu in yoruba
Capsicum frutescens – Tabasco pepper –Ata-wewe
Lactuca capensis – Lettuce – Yanrin
Bryophyllum pinnatum – Air Plant, Abamoda
Zingiber officinale – Ginger – Jinja, Atale
Dioscorea dumetorum – Sweet Yam- Esuru
Enantia chloranta – Awopa
Khaya grandifoliola, K. senegalensis. Oganwo
Sphenocentrum jollyanum – Akerejupon
Olax subscorpioidea – Ifan, Ifon
Tetrapleura tetraptera – Aidan, Aridan
Lecaniodiscus cupanioides – Akika
Lippia multiflora – Efirin-gogoro, Efirin-oko
Jatropha curcas – Botuje, Lapalapa
Jatropha gossypifolia – Botuje pupa
Jatropha multifida – coral plant, physic nut or
Guatemala rhubarb – Ogege
Cymbopogon citratus – lemon grass- Kooko-oba
Pterocarpus erinaceus – Apepo, Agbelosun
Pterocarpus osun – Osun
Pterocarpus santalinioides – Gbengbe
Catharanthus roseus - Apabida pupa
Carica papaya – Papaya – Ibepe
Dioclea scandens – Dasa
Dioclea reflexa – Agbarin, Epe, Arin
Lawsonia inermis – Henna plant – Laali, Lali
Ficus exasperata -Ficus Tree – Epin
Ficus asperifolia – Ipin
Ficus capensis – Opoto
Ficus elegans – Asoro
Ficus mucuso – Odan-afomo
Ficus thoningii – Odan-abaa
Ficus vallis-choudae – Ogunro
Vernonia amygdalina – Ewuro
Phyllanthus amarus – stonebreaker or Eyin-olobe
Mucuna sloanei – Werepe
Mucuna pruriens – Ewe-ina, Yerepe
Alstonia congensis – Ahun

Mangifera indica – Mango – Mangoro


Nauclea latifolia – Egbesi
Sorghum bicolor – Poroporo okababa
Senna fistula – Aidantoro
Erythophleum suaveolens – Erun obo, Olu-obo
Ocimum gratissimum – Clove Basil- Efirin
Telfaria occidentalis – Fluted gourd – Ugwu
Zanthoxylum zanthoxyloides – Orin ata
Acalypha wilkesiana – Jiwini, Ewe larapupa
Sida cordifolia – flannel weed – Iso-obo
Sida pilosa – Eesinle
Sida rhombifolia – Iseketu pupa
Thaumatococcus danielli – Ewe moi-moi
Azadirachta indica – Neem, Dongoyaro
Aloe vera – Ahon-erin
Aloe barteri – Eti-erin, Ida-egun, Ida-orisa
Garcinia kola – bitter kola – Orogbo
Ageratum conyzoides – Billygoat-weed, Imi-esu
Abelmoschus esculentus – Okra- Ila
Abrus precatorius -licorice – Oju-ologbo
Abutilon mauritianum – Furu
Acacia ataxacantha – Ihun, Ewon adele
Acacia nilotica – Baani, Booni
Acanthospermum hispidum – Dagunro
Acanthus montanus – Ahon-ekun, Irunmu arugbo
Adansonia digitata – baobab – Ose
Aerva lanata – mountain knotgrass – Efun-ile
Aframomum melegueta –Grains of Paradise Atare
Alafia barteri – Agbari etu
Allium ascalonicum – The shallot – Alubosa elewe,
Alchornea cordifolia – Ipa
Caesalpinia pulcherima – Eko-omode
Afzelia africana – Afzelia, Apa-igbo
Alternanthera sessilis – Reku-reku
Anacardium occidentale – Cashew – Kasu
Anthocleista djalonensis, Anthocleista
liebrechtsiana – Sapo, Shapo
Arachis hypogea – groundnut – Epa
Bambusa vulgaris – Golden Bamboo, Oparun
Baphia nitida – African sandalwood – Osun,Irosun
Allanblackia floribunda–tallow tree –Eku,Eso roro
Byrsocarpus coccineus – Amuje wewe
Calendula officinalis – pot marigold –Ododo Maria

Calotropis procera – Sodom apple – Bomubomu


Canarium schweinfurthii – Paapo, Origbo
Canavalia ensiformis – jack bean – Sese-nla
Carapa procera – Carapa – Abo-oganwo
Cardiospermum halicacabum –balloon plant
Shaworo
Celastrus indica – Ponju-owiwi
Ceiba pentandra – Araba
Cissampelos owariensis – Ewe jokoje
Chromolaena odorata – Siam weed – Akintola,
Tetracarpidium conophorum – Awusa, Asala
Vernonia colorata – Iron weed – Eriro-Ijebu
Xylopia aethiopica – Eeru, Erunje
Tridax procumbens – Igbalode, Muwagun
Waltheria indica – Ewe-epo
Vitex doniana – Oori-nla
Uvaria chamae – bush banana – Eruju
Viscum album – mistletoe- Afomo in yoruba
Uvaria afzelii – Gbongbose, Anikan wogba-arun
Urena lobata – Ilasa-agborin, Ilasa-omode
Uraria picta – Alupayida
Voacanga africana – Ako-dodo
Argemone mexicana – Egun arugbo, Ekan-ekun
Artocarpus altilis – Berefurutu
Boerhaavia diffusa – Etiponla, Olowojeja
Borreria verticillata – Irawo ile
Carpolobia lutea – Osunsun
Citrullus colocynthis – bitter apple, bitter
cucumber, desert gourd, egusi, Egusi-baara
Citrus aurantium – orange – Osan
Aspilia africana – Yunyun
Nicotiana tabacum – Ewe taba

AWAN OJO TIKO DARA NINU ODUN


aku ojuma gbogbo omo egbe ewe nje ogun nje
ojuma ire nio je fun gbogbo wa ooo opolopo eyan
niko ma wipe awan ojo kan wa tiko dara papa ninu odun
aman mafun gbogbo omo egbe yii lanfani lati fi ma awan
ojo tiko dara ninu odun. nkan tofi da ki eyan ma sunma
awan agbalagna niyen iru awan omo bee wan man da obi
( kolanut ) fun wan ki wan bale ma boya omo na mani
alamari rere nile aiye nkan toba wa jade lori re ni yio to wan

sona boya aiye omo na ma dara abi koni dara Obi ( kolanut )
dida lori omo see pataki pupo wan man see iwadi lori omo
naa nio
January :- 1, 2, 3, 4, 6, 11, 12 Feb :- 1, 17, 18
March :- 1, 4, 14 April :- 10, 17, 18 May :- 7, 8 June :- 17 July :
- 17, 21 Aug :- 20, 21 Sep :- 10, 18 Oct :- 6 Nov :- 6, 10 Dec :-
6, 11, 12 Boseri niyen ooo

AWON NKAN TI KII JE KI OGUN JE MO FUN AWON ENIYAN


.
(1) Aini imo to kun to lori ogun ti a nse lai mo ewe ati egbo .
(2) ogun kii je fun eniti owo aiye ba wa lara re .
(3) Aitele ilana ati igbese lori ogun jijo tabi lilo .
(4) Aini igbagbo lori ogun ti a fe se .
(5) Ailo ojulowo ohun elo
(6) Aisan owo ijeogun fifi sile lofe
(7) Ogun ti eroja re ko pe kii sise rara
(8) Aibikita boya eleda eniti o fe lo ogun ro mo . (9) sise tabi
je nkan eewo
(10) jije obe ila , jije eja atoko tabi jije okete loorekoore kii je
ki ogun sise lara .
(11) A ko gbodo ma dobo lati ehin
(12) A ko gbodo fi ise to ni agbara si ara ba obirin sun .

NKAN TI NBA IGBIYANJU ALAGBARA JE .


(1) Ma se yara maa joko si ibiti obirin bati dide (2) mase
maa to sori ewe kewe
(3) mase bi lehin aseje ti o je .
(4) mase tete lo gbonse lehin aseje ti o je .
(5) mase to sori ito inu ibaluwe
(6) mase fi omi iwe ti o bu nkan si fo ito inu ilewe
(7) mase maa yan kainkan re lehin iwe .
(8) mase san ese re lehin iwe awe pari .
(9) mase to sinu odo ti o ba nwe tabi ti o ba nlor
(10) ti o ba se eto iwe awelosun gbiyanju ki o pa ero
ibanisoro re
(11) ti e ba gba ise awesun, mase soro lehin re mo
(12) mase to lori apata tabi si ori ito obirin.
(13) a ko gbodo ma saba te opa aje wa sinu koto giri wo
won nigbati a ba ti lo ise loorekore
(14) a ko gbodo je ki obirin ba wa maa jo ise tabi ba wa

maa ja ewe tabi bawa lo ebu lori olo tabi bawa pelo aseje-
obirin miran ti won ti ju ifami
sinu kanga re ti ko we, beeni obirin miran yio ri nkan osu re
bi o ti se nba yin sise lo, beeni obirin miran yio gbe nkan
osu si oju ara ti yio maa ba wa sise lo-eleyi ko bojumu rara
(15) mase fi iyepe lasan gbo owo(hand) re
(16) mase wo ehin ti o ba lo we ose awebi danu . Mo duro
nihin na .

OGUN AKAWE MO RISE. OTUN SISE ITUWO.


Igbin apinnu Meji. Agbe mejeeji kale, toba ti bere sin faa.
Aoge ori won leyo kookan. Ao wa fi sinnu ape ijogun oyooto.
(Separately). Ao fi omo atare 9 sinu eyokan. Omo atare 7
sinu eyokan. Ao wajo. Ao lo lori olo otooto.
NOTE.
Eyi tafi omo atare mesan si 9. Aofi sin gbere round orun
owo otun ( right). Eyi tafi omo atare meje 7 si. Gbere round
orun owo osi (left). Ogun yi fun eyan kan soso ni.
Ikilo..
(Graduate) Hmmm. Bi eyan basi gbere yi sin, toba gbe si
rawon. Walai toba ni ibi totin manage die die tele, ise na
obo mon lowo. Afi kotun se ako ituwo to gbonna mi. Iba
ogami. Abdul Tijaniy Majeed Ad

OSOLE OWO AJEBIDAN.


Ewe iranje toni itanna dada, ao gun ohun nikan lose dudu
nibiti eda olohun kan koni tiriwa, ao kosinu igba olomori, ao
wa gbe igi ire( remi)
ni Ere obinrin, ao so ere naa loruko ( ale soni
akinremi eniola, lol), ao fi ere yii gun ose naa lori,
ao wa pa obuko ile toti gbo dada sori ose yii ti eje
yio mu ere naa dada, ao de igba naa pada, aowa fi aso
funfun bomale fun ojo meje, lehin ojo keje, ao pe oruko tia
soro ere yii lemeta pe lowa owo timaafi saiye wa fun mi,
owo ti maafi kole, ra motor etc, aso funfun laolo modi tia
ba npe oruko yii, aobu ose naa lowe, aso funfun laowo
through out ojo tiaba we ose yii, aso funfun naa laofi bora
mojumo lojo tiabawe.
N.B...
Akoni rin jinna sile lojo tiaba we ose yii. Ori
okuta ako meta tiafi se aro lao gbe ose yii si. Oju meji

kogbodo ri ose yii nibi tiaba gbesi. Ire ooo. Omo yoruba
nimi !!!

ASETA, MALUMI,MABAMI SOTA,MADARIKAN, MALUMI


ALADEHUN ENITO BA SA OGUN SIO SANPANNA NI YIOPA
Awo ekun tofe die, ao wa lo be igi ogirisako toga
pupo, ao mu wa sile, ti a ba de ile, ao be enikan yio fi igi
ogirisako yi won wa ni dede bi ati se ga mo, lati gigise titi
de ipako, ao wa te aso ibora wa ti afi sun silele lori cement
or ilele, ao wa fi igi ogirisako yi le lori ao we mo lara gegebi
eni di oku kale ao wa lo re gbe olo ti ao filo ogun yi ati omo
olo, ao fo olo yi nu daada ati omo re, ao da oju re ro ti yio
gbe, ao wa tu aso ti ate kale ti awe mo ogirisako yi, ao mu
obe ao ha gbogbo egun ara ogirisako yi pelu pele pele, ti
aba ha tan ao wa fi pele pele gba egun yi jo, ao wa gbe olo
ka ori aso ibora ti ate kale yi, ao ko awon egun yi le lori ati
awo ekun yi, ao lo lori olo towa lori aso yi ti yio kunna daada,
ao wa te odu osa meji le lori, lori olo ti agbe ka ori aso ti ate
kale yi, ao wa pe gbolohun yi si
Iwo sanpanna mofi owo mi mejeji ba o mule loni Mo fi ese
mi mejeji ba o mule loni, Mo fi emi mi ba o mule loni. Mo fi
obinrin mi ba o mule loni Mo fi awon omo mi ba o mule loni
ati gbogbo ohun ini mi pata, ni mo fi ba o mule loni, Gbogbo
eni toba sa ogun si mi iwo lo sa ogun si Gbogbo eni toba bu
ese mi iwo lobu lese Kogbodo ran emi lagbaja omo lamorin
Gbogbo eni toba sepe lemi iwo lo sepe le, ko si baja,
Gbogbo eni toba lu mi iwo lo lu ko si baja ,Oo si gbodo gba
ebe re Bi obinrin mi ba lu mi, ma baja oo Bi omo mi ba lu
mi, ma se baja oo Bi omo omo mi ba lu mi, ma baja o Ao ka
gbogbo awon ti a ko fe ko baja si pata Ao wa fi ebu yi sin
gbere lati aaye ibiti irun ti bere si ni hu loke igi imu yio gba ti
amuje koja lo, yio pin ori si meji, yio gba ti ogoro eyin lo titi
de aaye ti awe idi mejeji ti papo leba lago lago furo mejeji,
ao fo gun yi ra opari

EYONU TI ABURU KI FI WOLE TI ASIRI WA YIO SI MABO


ao lo wa erele ewe abo ibepe ti yio po die, ao wa lo ti yio
kuna dada, ao wafi te ejiogbe si oju olo, ao pe oforo re si,
ao wafi ose dudu ko, ao mafiwe lararo.
OFO RE:
aso logbo... hmmmm epade mi ninu group 'olorun loba asiri

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125


million titles without ads or interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.

ohun gbogbo' nibe ni eo ti ba ofo ise yi pade.

KI EYAN MA KO OKUN ELENA MO:


ao wa ewe onitikuti, ao gun mo ose dudu, ao fi epo para, ao
duro bi iseju ogun, ao lo wa we lale tia ba fe sun.

ASIRI BIBO
Ewe imiesu, ewe tagiri, ewe sawerepepe ose dd ao po mo
ori Dada ao mafiwe opari

odidi ila totiko kan eso werenjeje koniye ewe apada koniye
omo inu atare koniye aojopo gbere yipo ikun etun fi die
fokomu ire ooo

ASHIRI OHUNMON FUN 1960 TABI BABA IJEBU TODAJU-


ori akala kan,odidi omo olongbo dudu tikolaju,eja ojiji aye
3,iye agbe kan,ori igun kan,eyin eiye alapandede 3,oga aye
3,aso waji gidi tofe die,aso awon agba gidi 3,eku emon
meta,eiye kanna kanna 3,odidi atare aja meta,aso igunnuko
gidi die,ao ko gbogbo nkan yii sinu ikoko tuntun nla kan
pelu eiye etu naa laaye,ao wa fi ikoko nla keji boo lori,ao wa
jo iseyi ninu igbo,ao gbodo jo ni arin ilu rara o,ki a to jo
iseyi,ao fi iyere osun gidi te ifa OSA MEJI si oju aro naa,ao
wa bu epo pupa si oju odu naa,ao wa ada gunle nidi aro
naa,ao wa dana,ao gbe ikoko na si,ti a bajo tan,ao jeki ina
ku patapata ni idi aro na,ao wa lo kunna daada,ao wa ro
ebu yen sinu seere nla kan,ao wa gbe sinu apo aso funfun
kan,leyin ti abati gbe iseyi dele tan,oju meji  Ikogbodo
ri mo o,beeni kogbodo kanle rara,tio badi ojo keta ti a se
iseyi ,ao pa eran obuko kan fun ise na,ao fi igba kekere gba
eje eran yen si,ao gbe eje yen losi idi ibiti ise naa wa,ao
koko fi eje yi fo owo wa mejeji,ao tun fiwe oju wa naa,ao wa
gbe eje toku ninu igba yen si ibiti a gbe ise naa si,ao wa fi
eran ti a pa yen se saara,ao gbodo je ninu re o,tio bape ojo
keta ti a se saara yen tan,ao losi idi ise naa ni aro kutu
kutu,ao ni ba eje naa ninu igba yen mo,ao wa bu ebu naa si
owo alaafia wa,ao teni ifa OSA MEJI,ao wa fi oti schnap loo.
AKIYESI-
ao gbodo mu enikankan losi inu igbo ti a ti fe jo

ise yio,osu meta meta ni ao ma lo iseyio,pelu saara re,bi a


se se saara alakoko beeni ao se se elekeji na

EYONU TON FAREWA NI KIAKIA


Odinde eye igun kan ikodide 21 eru tikoti laju ige
eran elede alangba adanripon ewe ola tutu ewe aje tutu
ewe iyalode pupa tutu ewe kole orogba toopo pelu odindi
atare kan ao jopapo ni owuro kutu ojo aje ao wa pomo ose
gana ao fi owo tuntun te isale awo funfun tiko ni abawon
ao gbe ose na le lori ao mafi we ni gbogbo ojo aje sugbon
kise ninu baluwe ti gbogbo eniyan man we sioooo

OBA-EMI [ASIRI WOLI]


isori ti mo yonda yi,hmmm,ao le mo iyi re rara bur elo
danwo..ao du adaripon lati ipako,ao fi ejere yi eyo atare
kan..ao sa gbe,ao lo,ao fi singbere eyokan si ori wa...kasa!

Ogun ki alantakun ma ta okun ko eniyan lori.


Ao to ito (urine) akoko lago mejila si ago kan oru, ao gbe ito
(urine) yimu lago meta oru, a o fi eyi toku bo oju wa, ao wa
agbon meta to lomi ninu, ao fo meteeta lago marun idaji, ao
fifo ori wa si ibi ti ile ti le fa omi re mu. A jee fun wa.

ETO ILEKE IFERAN RIRE


Ope oyinbo ti o pon dada,ao sa ni pansan, ao ko
ileke to ba wunwa sinu re,ao ko sugar mewa si,ao fi adun si,
ao gun ireke ao fun omi ireke naa si,ao wa da oyin igan si
pelu ao wa de pelu omori re,ao wa ree fun ojo mesan 9, ao
wa sa ti yio gbe ao wa ma fi ileke naa sidi. Odaju ooo
okunrin le ta gbogbo nkan toni oo ko se fi sere ooo

ISORI AWON OTA


Ori ejo agbadu ka epo obo atare kan ao jn po ao ro sado ao
ni de enu ado yen rara ooo ao wa di
nikobere ao gbeko senu ona yara wa ninule ISERE
Eniti o ba sa siwa laburu ejo yio ge eni na je nio
odaju KILOMODEMO

ASETA TODAJU
Ewe eyinolobe ao gun pelu epo obo leyin odo pelu ose, ao
ko sinu ike funfun odi wiwe.

AYAJO ASOGBA TODAJU SAM SAM


ao pe ayajo yi sinu omi ao mu ao fi boju wa kato lo ba eniti
a fe basoro na
OHUN RE
abara waiye loruko tanpe omi omimilolo omi lama mu sun
omi la mu ji to baje omi ati eje ni nwon fi bi langbaja omo
langbaja ohunkohun temi langbaja omo langbaja ba so fun
langbaja olangbaja ni kio gbo kin gba ko se ohun bayi
bayi #ANIYAN WA fun mi #KILOMODEMO

KI AWON AJE MOJU KURO LARA WAAAA


Eso koro isin dudu kan soso oko atare kan ao jo po ao fi sin
gbere eyo kan soso si oke iwaju ori wa
NOTE
Aje ko ni le woni loju titi nse ni oju re yio ma somi perepere
nipa bayi nwon ko ni le dini lowo mo odaju paaa
#KILOMODEMO

AWURE TO DAJU
Dr. Praise (Omo Iyin)
Ewe tagiri tutu, obi ifin abata, obi ipa abata, ao ge won si
wewe, odidi atare kan, ao bo epo ara re kuro, ao yo gbogbo
omo inu e ti ko ni ta danu, ao wa gun yio kuna daada, ao wa
po mo ose dudu, ao le mo ara ogiri, ao ma fi we....Angeli mi
o ni sun

Eniti ota ba poju fun yala ota ile baba,ota aseyori,pelu ogo
olorun ti enia bari ise yi se ni e kokan awon ota re yio subu
niwaju re.
ORUKO MIMO OLORUN LATI LE BAYE OTA JE.
ao wa abela dudu kan,ao wa tan siwaju wa ni agogo kan
oru ao wa ma so awon oro yi nigba meje ao wa fi abela na

sile ko jo tan,ao wa ha ajoku abela na ao lo da sinu omi


egbin,pelu Ase olorun wa ni isegun Lori ota re. Mopase fun
yin eyin emi airi toni agbara julo,eyin ni emi ti o ma nfi edidi
di gbogbo eda enia ati alujonnu lenu,mo wa fi Ase oruko
mimo olorun yi
HAUSAMI,BARASIMI,KAAHI,HIYAA,SHARAHIYA,ADONAYA,
ZEOBAOTH,EL-SHADDAYA.
ko gbogbo ota mi ati awon alatako jo mosi fi opa mose lu
won,mo jagbe mo won pelu oruko mimo olorun
mokandinlogorun,moti pa won lenu mo ki won ma le
soro,moti so won di odi,won tidi afoju ,won koni le riran ri
aye mi mo,won ti di ayaya won koni le soro rara,ayafi ki won
so rere nipa mi,bi won tile po ju milo,ti won ga bi oke ti won
si lagbara jumi lo olorun bami re won sile bi o ti se re ile sile
ni Abe atelese,ao wa se adura nkan ti afe fun awon ota wa.
Iwulo ise yi po gidi gan nio lodo awon enia olorun sugbon
gbiyanju iyen fun ota re. Gbiyanju koni Iwe aditu orun lowo
ati powerful handkerchief.

IFERAN OBINRIN
Ao lora lofinda meta, ao fun obinrin ni agbon kio fi omi
agbon na tanba abe re, aofi gbo ewe sinkirimini ati ewe anu,
ao wa fi ajo elubo se, ao wa da mo lofinda meteta, aoma fin
si ara ja de Sugbon obinrin yio po gan ooo

OGUN AWEBI DANU


ewe ejinrin pelu ori ao gun pomo ose dudu ao ko sinu ike
funfun ao koko lo fi we ni odo ton san kia to ma fi iyoku we
ni ile

OGUN OHUN
Eyo atare 201 obi funfun alawe merin eyokan, orogbo meji
ao gun papo ao da sinu oyin ao ma la ao si gbudo ma mu
omi tutu ju mo

Iferan obinrin todaju


ewe amunimuye,odind atare kan,ewe akonimora, ewe
omisimisi pelebe,orogbo kan,obi alawe meta, ao jopo ao bu
si atelewo ao mafe danu pelu ofo yi

amunimuye mu iye lagbaja funmi,akonimora ko ife mi si


okan lagbaja,ki lagbaja mafami Mora ,igbagbe se orogbo
kolawe,igbagbe se obi kolawe ,lati eni lo ki omalesun ayafi
ti obarimi haa iseyi yawere gan ooo

ADO IWOSE,,
iyepe okun,iyepe osa, ori ijapa, okan akuko adie ,ao lo
gbogbo re kunna dada, aoro sinu ada tiaba felo, ao fi aso
pupa di lenu,,tia ba felo,, ao te ado naa sowo ,ao pe ofore,
ao pase nkan tia ba fe kiose fun wa
,,OFORE,,
olukiki,olukilumon3times, bi ojumo bamo olosa alukiki,
ojumon ki jeki awun sun igbe, kio dide ,tio baje pe ohun lo
gbe nkan naa,(yio si dide), amo lenu ojo meta yii enikon
kon,o post ,ejor, eje kama je anfani arawa, see u next time
with AGADA-GODO AKOYA.

TIWON BA GBA OKO ENIYAN /ADAKOLE /OKO TIKO LE


DAADA /TOBA NDEDE RE OKUNRIN LASIKO ERE.....
Eso tagiri eledanran, complete iru lagaranta, iru oka, eso àti
èwe panle isale, wonranworan, odidi Ako ijapa, ao gun
gbogbo re papo mose, ao kosi inu igba ijapa yen, ao fi igba
Aya re de..... Fun eniti won gba oko re, yio ma fi omi gbona
ji we laro kutukutu, omi tutu lale, oko tiko lè daada, ao ma fi
we ni araro, idakole wiwe pelu omi gbona lale tutu lararo,
eni ton dede re, ko ma fi we anytime....

Eto Iferan Todaju


Ori Okere Kan, Ewe Ebolo, Ewe Odu, Gigun Ao Wa Po Mon
Ose Eyikeyi Fun Wiwe
( Odaju Ni O ,eyewo Sir/ma)

OSE ASINA AWON AGBA


obi aba alawe merin kan iyo obe epo pupo ao lo po ao po
mon ose ti ale fi we fun ojo mefa ojo mefa ni ao fi we ose
yii ao si so kainkain ti a fi we ose na nuu...

ASINA EYONU OWO


ewe ajeobale ojoo ti opo dada odidi atare kan
ao jo po ao wa pali sugar st luis ao ko gbogbo line oke ao
lo po mo ogun ti ati lo yen, ao fi sugar toku se sara ao ma fi
omi lo ise yii ni araro... yio bawa lara mu mi o ni fi number
mi kale tori kosi oro mo lori re bi o se ri ni mo so yen.
sugbon ele pade mi ninu #EGBE_ASIRI_AIYE.

OBA OSE AWURE


ose dudu abo adie ti o ba ti pa omo ri obi abata meji itakun
ata ti nka ni ododun odidi oga kan ewe iroko ao jo gbogbo
re papo ao po moose dudu ao pa adie yen ao da eje re si,
eniti yio lo ko gbodo je ninu adie yii oooo ao ma fi ose yi we
pelu karinkan tuntun ao ko sinu igba olomori, akoni jade lo
ibi kankan lojo ti aba ti we ose yii...
OFO RE:
Igba onigba, awo alawo ni iroko fi n to ile ore olore di temi
loni owo olowo di temi loni ori ata kii da fun omo nigba
kankan ki owo ma se da lowo mi aba ti alagemo da ni orisa
oke ngba ao si se opolopo adura si
AKIYESI:
ilele ni ao ti po ose yii
EMI MI YIO OGUN.....
Emi omo yin na ni oooooo Fun ise miran ele pe mi
08062162864 #EGBE_ASIRI_AIYE npe gbogbo wa
www.facebook.com/ymartize

OGUN ISIJU / AFERI TO DAJU NI ELEYI.


Orogbo kan, ao ge sona meji, ao fi nkan ho inu re danu, ao
fi kokoro itale kan (kokoro yi, a maa nri ninu iyepe ile ito
nibiti ito nsan gba labe okuta tabi ninu iyepe re la maa ti ri,
o funfun bii idin (Margot) to njade ninu eran / eja to ti baje),
a maa diju wa ki a to mu itale yi sinu re pelu eyo atare kan,
ao fi ikeji re de pada, ao wa laju wa, ao we lowu dudu ati
funfun, ao sese wa tun fi aso waji bo daadaa, ao tun wa we
lowu dudu ati funfun, ao lo re sinu omi aro (omi aro ti a nfi
si aso, sugbon odo awon to nre aro ni a maa lo re si ninu
ikoko won) fun ojo meje (7days), ao lo ran ni ikorun pelu
awo dudu.

You might also like

pFad - Phonifier reborn

Pfad - The Proxy pFad of © 2024 Garber Painting. All rights reserved.

Note: This service is not intended for secure transactions such as banking, social media, email, or purchasing. Use at your own risk. We assume no liability whatsoever for broken pages.


Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy