Iwe Ogun PDF
Iwe Ogun PDF
Iwe Ogun PDF
Iwe Ogun
Uploaded by Ifasegun
Document Information
By ifasegun
OriginalDownload
Title now
Iwe ogun
Copyright
1© © All Rights Reserved
OHUNMA_ISE_WIWO_TI_KII TASE AN
IYAN_ONIBERE.
Available Formats
Ori Olongbo tonirun1, Ori eiye owiwi, Ori ekute ile
PDF,
tiwan TXT
pasi or read
oju-ona, Ori eiyeonline from
kaaro, Odindi Scribd
atare1, Ao jopo ao lo kunna,
ao rosinu ado kekere kan, ao kokofi fokomu fun Odindi ojo meje lera,
2 EGBE OWO
aowa oga gbigbe meta, atare odidi meta, 200 tuntun meta aojopo aomafi milk lo larolaro
Facebook Twitter
3 OWO (RESPECT)
aowa dagunro ao fisinu ape ijogun aofi atare kan si aojopo aofisingbere meta meta si orikerike ara
tabi ki Fi blade tuntun je ebu na
4 *OSE ATUDE TOJE*
Asinrin tutu 1,ewe asa tutu ,epo obo,igi nla,ewe egele tutu,ayan pupa 7,aogun gbogbo repo
Email
Dada,pelu ose lopolopo,aoko sinu ike funfun.....lilore......
Omi tutu larooo
Omi gbigbona lale.
7 *OSE ATUDE*
Ata ijosii 9,epo obo die,aolopo,ose iwe kan,aowa sebe lona mesan,aomonfi epopupa para kato
we,ojo mesan.
.....odaju.......
*
8 OSE IYONU*
Esuru pupa, aogun papo mon kanhun billalla orijina,aokolose aomon FI omii gbigbona we lale......
*
9 OSE RIRISE *
Esuru pupa,aogunpo mose lopolopo, adie pupa ejere laofipo osenaa,aolori adie na mo,Ori
akitan,aomon FI osena we lale pelu omi gbigbona.... Odaju
...........
16 BIBO ASIRI TARA FUN GBESE OR INANWO. Edon maalu ti won oti ki bo omi ao ge si 9. Irun
iya mapo. Iyere 9. Epo jebo.ao lopo ao fise edon yan lepo niyo.ti oba jinon ton ao fi iyere osun te.
Eji ogbe. (404) IFA nin saya ogun, ogun nin selegbe leyin re, obatala nin daso roni, aiba jigijigi
lorun gbese, bomo kekere baje gbese jebo ninbo jebo aba San. Bagbalagba baje gbese jebo
ninbo jebo aba San asabo ni ti jebo. Irun nin basiri obo. Ati egun ati eron ati awo nin basiri Edon.
Eji ogbe walo gbe owo temi fun mi wa o.ati okunrin ati obinrin omode agbalagba ki won wa bomi
lasiri kin ri owo yi son o. Adua ao wa da iyere osun yon si odi jije.
17 ASINA
ao han bismilahi 12000 ao Fi omi ti eyele muku fo aojo awo lili tiwon bo pelu Ori re ,obi abata ati
orogbo kan,atare kan aojopo aoma Fi hantu ye loni gbogbo igba
18
ITUWO AGBA
Igi nla, epo obo,eru awonka tikokan rara ,epo igi ose oojo,aogunpomo ose dudu ,oronro malu
laofipo ,aso egungun laofimawe
19 ERO ASASI
ewe labelabe topo die,
Odidi alakan oke tope kan,
Iye igun kan,
Aojopo,aomafifokomu nigba tobawuwa pelu ohun re opo eyan lelo
OHUNRE:efun kin mu igun 3*
Edi kidi alakan 3*
Bi omo kekere basare wonu labelabe eje abo 3*
Bi agbalagba basare wonu labelabe eje abo3*
Obinrin ni okunrin ni ,omode ni,agbalagba ni,woli ni,pastor ni,alfa ni,baba alawo ni,onisegun ni
won bansa si emi lagbaja omo lagbaja ki eje mabo won ni
Formula :- aogun gbogbo re papo mo ose toto we ni ojo emeta, aowa pin ose yi si ona meta aofi
we ni ojo meta tele rawon, aoma fi epo pupa para kia towe
21 ASINA OWO
Ori ewure,Ori aguntan, odidi atare kan, aojopo aoda ebu re simeji aopo idakan mo ose,idekeji sinu
shinap aomafi ose we aomamu shinap na larolao,
23 AWURE OWO
Ao ju ewe tapa tutu pulu ito ajito ao pomose ao kosinu ike funfun odi wiwe lojo meta meta
24 OSOLE
aowa Ori olongbo tonirun kan odidi atare kan,eso laa pupa aojo aowa Fi 1000 tuntun kan, sinu igo
shinap aowa da ebu yisi aomamu ni aro..
27 ASINA OSOLE
Igbe adie Inu kuku, epo obo Epo igi nla ekolo ao gun Mose ao ma fi we lale nikan. Ao koko mu
epo pupa ao si tun fi para kia to we nitori kio mo ba mu eje wa
28 ASINA
Ako alangba ao ko ewe ewuro oojo le Lori padi atare 1 ao jopo ao lo kunna ao mafi epo pupa la
die die lalale
29
OSOLE
Lekeleke 1 eyele funfun I, ewe abamoda topo padi atare 1,ao jopo ao mafi fo eko mu lale
30: IWE ITUWO AYE,Egbo igi Akoko ,epo igi Akoko ,ewe Akoko ao gun meteta yi po kuna pelu
ose Dudu,ao fi epo pupa po ao pinsi ori Lankan meta, ago kan oru no ao we ise fun ojo meta,kerin
ao mu igbin agbonu kan ao sokumo karahun re igbin yio famo igi Akoko yi,APA into igbin yi towa
Lara igi yi ao fi obe han rare,ibibti igbin yi ranmo aolo pelu iyere ao rise igbin naje ,to olorun bawo
loke ide maja
31 OSHOLE
oloungbo toti ya wanna 1.ao pa ti Eje re koni kan sile, ao la laya, ao fi owu tutu tele inu re, ao ko
orogbo 11 ati obi abata Oloju merin, 4, atare 11. Ao ran pada ao wafi ewe ejinrin bo ni gbogbo ara
ti koni yosita nibi kankan, ao gbe sinu agbada, ao wa Epo pupa, ori, ati adi eyan, ao da papo, ao
gbe si orun ti yio yo papo, ao ma tasi ogun yi Lori ina tio fi jo tan,ao Lo ninu agbada, ao mafi oti
OYINBO lo laro laro. Wahalahi talahi sunmobila lasi ise unla ni
34 AJEGUN to confirm
Ao wa awo eta pelu EYO at are mesan, ao lo tiyio kunna ao wa fisin gbere yika orun wa mejeji aje
35 ATUDE TO DAJU
Oro agogo, epo obo ewe mafiowokanomomi ao gun papo mo ose dudu ao fi tutu po papo mo ose
dudu ao San bante mo idi tao FIMA we, pelu ogo olohun eni toba gbiyanju mejeji yio dupe fun
olohun..
36 OGUN ASETA
Eiye kanakan eyo kan, ewe isu jije, haha agbado towa Lara agbado, odidi ladoripon kan, ao gun
papo ao po lose, ao KO sinu igba onikoko taba FEMA buwe ao ofo re, koko se hahaha si lemeta
ewe isu kigbe Ara isu koka odun, haha agbado kigbe Ara agbado koka OSU, ako ladoripon kilo
erun meji papo, bi kanakana bami igba ota niwaju Ohun buruku loma bawon, bi kanakana bami
igba ota leyin Ohun buruku loma bawon, Ohun buruku Niko maba awon ota mi,LATI oni lo ao lofi
ose naa we.
37 AFUNJE IFERAN....ekana owo mewewa ekana ese mewewa eyo ere kan awa sin gbere
larawa ejemajade nibe ao fi ere yen nun eje yen dada awalo meteta yen papo ao fun obinrin nan
je
38 OGUN IDENA TI OWO KIFI SOWON LOWO EYAN, MOFI ISE KI BABA WA OBASEGUN KU
OJO IBI WON.
Eran malu ekiri kan ao gesi mewa, ataijosin mewa, ewe iyalode mewa, ao lo papo ao kosinu
isasun ao wase tiyio jinna ao sokale Toba di ago mewa ale, ao gbe isasun yen siwaju wa ao bora
si ihoho ao wamun ekiri eran kan ao sope eyin aye egberun lonaa egberun ti efunmi moti lontan,
efunmi nimi, eyin aye egberun lonaa egberun lonaa egberun ti efunmi moti lontan efunmi nimi, bi
asemafi niyen taofi fije mewewa tan, taba tije ao lofo isasun yen Nita gbangba.
39 ISOYE....eye awoko eye enga ewe oniyeye odidi atate kan jijo po inu oyin lila
40 IFERAN GBOGBO ARAYE...awo ekun egbo ogbo abere eyo atare mesan jijo po ao wa dasinu
lofinda ipara ao ma fi para die
41: AWO IGBA AISAN......tagiri kan awa gesi wewe bara kan awa ge si wewe epo osan wewe eru
alamon kanhun bilala awusa tutu ata adayeba jijo po ao da sinu omi osan wewe mumu lemeji
Cancel Anytime.
Download