Itusile Lowo Oko Orun Ati Aya Orun Ati Efiji Buburu
Itusile Lowo Oko Orun Ati Aya Orun Ati Efiji Buburu
Itusile Lowo Oko Orun Ati Aya Orun Ati Efiji Buburu
1. Nipa eje majemu Jesu mokede ikosile fun oko orun/aya orun to muaye mi leru.
2. Nipa eje majemu Jesu mo jawe ikosile fun oko orun/aya orun ni oruko Jesu
3. Iwo orisa idile to duro gege bi oko fun mi ni ipele terhi gba iparun ina nipa eje Jesu.
4. Ale ti omo oko orun/aya orun lori iseda mi pare nipa eje Jesu
5. Eje Jesu yo awon emi okun kun lenu nitori ominira mi ni oruko Jesu
6. Gbogbo ibinu oko/aya orun ton da aye mi lamu ati igbeyawo mi pare nipa eje Jesu
7. Iwo ikoko majemu, oko orun/aya orun ninu aye mi nipa ara ati ina fo danu ni oruko Jesu.
8. Iwo emi orisa idile oya nipa ina tu igbamu re lori aye mi ni oruko Jesu
9. Jeki gbogbo pepe ibi labe omi komi nibi ti nwon ti nsise ibi lodisimi parun nipa ina.
10.Agbara kagbara labe odo tabi okun tin won nlo lati dari aye
Mi lodi,parun nipa ina.
11. Mo gba ara mi jade kuro ninu igbamu oko-orun ati aya orun loruko Jesu
12. Gbogbo Jigi ibi Alayanle tin won fin so aye mi labe omikomi,parun loruko Jesu.
13. Orukokoruko ti nwon fun mi labe omikomi, mo ko o, mo si pare nipa eje Jesu loruko Jesu.
14. Gbogbo aworan tin won gbekale labe omikomi lati se ayidayida mi, yangbe nipa ina loruko
Jesu.
15. Mo fo gbogbo majemu eje ati asopo ibi pelu oko orun/aya orun.
16. Iwo oko orun/aya orun to n pon aye mi ati igbeyawo mi loju, mo gbe o de mo si pa o run
loruko Jesu.
17. Gbogbo ogiri to wa laarin emi ati ibewo Olorun sinu aye mi,wo nipa ina loruko Jesu.