Document

Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 10

Saturday, September 30, 2017

IPARA AWURE TODAJU "


ao gun iye agbe meta, iye aluko meta, ikode meta, ao gun won papo mo osun pupa die, ao wa teni
ejiogbe, ao pe ohun re si, lehin na ao da sinu adin agbon.
OHUNRE :- olayemi awo won lode egba, oladewa awo won lode ijesha, onhan onhin ohun ewa ni
won jonwo ilu, agbe kiti ni maro, aluko kite ni mosun, odidere kiti ni mako, oro emi lagbaja omo
lagbaja Di osun, odi adin momu kun ori, momu kun gbogbo ara, ki oro mi jasi eyee larin gbogbo
eniyan nitoripe agbe kiti ni Moro kinmasete larin egbe o, aluko kiti ni mosun, odidere kiti ni mako
kinmase te lowo oso, aje, elebologun, emere, asebi aiye, lowo okunrin ati obinrin.
Ao wa mafi para wa ti abatinjade. Odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 6:26 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

OSE AWENU TODAJU "


egbo tude ati ewe re, isawuru meje toni omo ninu, eso oju olongbo topo die, ata ijosi die, epo obo
die, igi nla die, ao gun won kunna dada mo ose, ao ko sinu igba olomori kan, ao DE pa, ao ge
pamo fun ojo meje, ao mafi we lehin ojo keje pelu fifi epo pupa para Kato we.

Posted by Olatiboye Mutiu at 6:26 AM No comments:


Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

"ASEJE ASINA OWO TODAJU"


aseje yi daju tara, gbogbo eni keni toba rise ki olohun fi alubarka si.
Iye agbe kan, iye aluko kan, ori eye owiwi meta, ao gun kunna dada pelu ata ijosi iyekiye tabi
iyere, ao wa fi se oju malu 32 je lepo niyo, ao so sori osuka aso funfun, ao se adua si, ao wa je,
any time ni jije re.
Posted by Olatiboye Mutiu at 6:25 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest
Wednesday, September 27, 2017
ISORA TOBURU TI A MAA NFI NRAN OKU SI AWON OTA
Ao han Suratul Masad Meje sinu paper funfun kan, Ti aba de ori Elekeje, Mim to pari re ao bu
Mim yen ti yio fe daadaa, ao da aniyan wipe gbogbo eniti nba nperi Emi Lagbaja nibi Okunrin ni
o, obinrin ni o ti won nba nsa Ogun buruku simi ki gbogbo won ki won maa ku kotodi ojo keje,
lehin naa ao lo wa Iyepe oju titi ti motor ngba daadaa gegebi Express way, ati iyepe sare okunrin
ati obinrin, ao fi se gari tira naa, ao di ni owu pupa, ao lo ri mo ori sare oku ti won ti sin tipe tipe.
tobadi Ojo keji ti ase ise yii ao bere sinu saa Suratul Masad 1000 fun 7 days. Ti abalagbaara ale fi
awe gbigba se adua naa fun 7 days,
Laye awon Ota yin baa baje. Gbogbo ala yin ti e baa nla lehin adua yii, Ala isegun ni.
Posted by Olatiboye Mutiu at 3:53 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Saturday, September 23, 2017


OGUN TI ORUKA BURUKU KONI RAN WAA TI WON BAA KAA OUNDE TABI ORUKA
BURUKU LU WAA, ORUKA NAA YIOLO DAHUN PADA LARA OTA NAA
ako alangba kan, odindin ataare kan ao jo ao lo kuna, ao di si ibi kan, ao tun jo abo alangba ati
ataare kan papo, ao lo kuna ebu mejeji ko gbodo kan ara won oo, ao sin gbere si oke ikun waa ao
fi ebu ako paa ibe, ao sin gbere round isale ikun waa ao fi ebu abo paa oju gbere naa, opari,

opo enia le sin. bi won baa fi ogun buruku naa waa ha?????????? aiye enia naa baje
Posted by Olatiboye Mutiu at 1:53 PM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Friday, September 22, 2017


ASEJE BIBO ASIRIBIBO Ao ge igbin apinnu meji si 25-25, Ewe Tanaposo 25, ododo tanaposo
25, iyere 25, N1000 tuntun tabi iru owo ti o ba tobiju ni ilu ti aba waa ao ko oruko wa ati oruko
iyawa wi oju mejeji owo naa, ao lo peli iyere 25, ao lo gbogbo re papo, omi hantu Suratul Wakiah
kan lao fi se paseje pelu epo ati iyo, Olohun yio biya Bukata eni ti o ba je aseje yii ni osu naa,
odaju samu
Posted by Olatiboye Mutiu at 9:43 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest
Wednesday, September 20, 2017
ADURA TIAFINKOJU EYIKEYI ISORO YALA OGUN OTA, OGUN IDILE, ABI EYIKEYI
OGUN AIFOJURI TONBA OMO ENIYAN FINRA TIKOJEKI ONI ILOSIWAJU NINU IRIN
AJO AYEERE TI OBATI JA EWE TOSITI WA EGBO TOJEWIPE OJU KAN NAN LONJASI,
IWO OMO IYAMI DAKUN NI IGBAGBO KOSIGBIYANJU ADURA YII WOO HNMM NINU
EPE NINU ADURA WAASEKAN Aowa aso pupa, aoran ni deede sokoto ewu, ati fila, tobawadi
deede agogo mejila abo oru (12:30a Aose Aluwala Aoyan Nafilah Rakah 2, Fathia 99 Lori iduro
kookan, aonikaa surah kankan leyin re, aowa salamo, sugbon origun mereerin laoyan nafilah meji
meji yen sii, aomaasalamo ni origun kookan, leyin salamo aodojuko kiblah (gabasi) aomu tesbah
aose ISTIGFAAR........1000 ASALATU ALA NABIYYI........1000 HASBUNALAH WANIMOL
WAKEEL........4 050 Aodide aolosun, aosebee fun ojo meje, leyin ti ojo meje bape..........Aodin
akara elepo pupa, abi kapa adire akuko totobi daada, aofise sahara, hnmmm Ti oro eeyan
kobatiidebi wipe kofeeni ojutu Mon kodakun komase iseyii ooo, bi iseyii se rora kere mon,
wonmanfi pa ota tobako tikofeejawo ninu oro aye yan nii ooo,,, aiye oni muwa o, gbogbo Lao
segun awon ota wa ola anobi Mohammad,,, ameen. Omo odo agba worldwide
Posted by Olatiboye Mutiu at 8:55 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

AGBO AISAN KI AISQN NINU ARA Ewe Pear ao ja kopo die, ao se ni agbo fun mimun gbogbo
aisan ara lo nsise fun odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 12:55 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Tuesday, September 19, 2017


AWURE OWO ewe Tomatoes ojo topo die,igbo ti won mu Ku,ao lo won papo mo ewe onitikuti
yen,iyere die,ao fi se igbin toba pinu kan je,lepo niyo,ao wa mu oti star meji le Lori.
Posted by Olatiboye Mutiu at 10:19 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Monday, September 18, 2017


OGUN AWURE : a o wa ewe agogo igun tutu , eru Alamo, a o gun mo ose dudu, a o fi iyeru osun
te ifa ika meji , a o pe gbolohun si , a o dasi ose yi, a o po dada, a o gbesi ilenle igun ile, a o pe
gbolohun si , a o so fun pe ose na pe Iwo ose yi , aini owo lowo ni mofi ko e si ilele nle, ti oba mu
owo wa fun mi , inu igba golu ( gold) ati fadaka ni unko o si , a o ma fiwe laro. gbolohun re :
moyo nje moyo, moko nje moko, lodifafun orunmila, tinfi efufulele yo lojojumo aiye, oni olowo ti
mbe lapa okun ki owa jemi, oni olowo ti nbe lapa osa kowa jemi, ika meji Iwo loka ire gbogbo
aiye , ki o loka olowo wa , ki owa funmi lowo, ki olo ka olola wa, ki o wa fun mi lowo. .........
Posted by Olatiboye Mutiu at 10:31 PM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

IKEDE PATAKI Eyini lati so fun gbogbo awa ololufe blog yii wipe, ati nse ipade ojukoroju ni
state kokan, ilu kokan fun ilosiwaju ewe ati egbo, ati lati ma fi Awon unkan ran arawa lowo, ori
what's up lati koko fe bere eto yii, lehin naa ao maa se ipade ilo siwaju egbe yii ni fave to face.
Eleyi ni awon Zone ti o ti wa nile bayi, ki e add what's up link naa lati join IKORODU ZONE
https://chat.whatsapp.com/164IhdY3vj98nDDN9YBW10 IJEBU ZONE
https://chat.whatsapp.com/D8iIDyAQnIs9SeJfacLCYG ABEOKUTA ZONE
https://chat.whatsapp.com/EvxNeiYpRJg6PGkoeZcHJP SANGO OTA ZONE
https://chat.whatsapp.com/9kg4sxIVTEx72kGnd4UDvj IBADAN ZONE
https://chat.whatsapp.com/KLKhoGcd4W4JBevDH1sK8h YABA AND ISLAND ZONE
Posted by Olatiboye Mutiu at 9:59 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

OGUN AFORIJIN : a o wa ewe orijin tutu die , iru die , iyere die , a o lo po , a o fa sinu isasun
kekere kan , a o fi epo si ati iyo , a o fi se eja aro je , ti Oba jina , a o so sori osuka , a o so wipe ,
iwo lagbaja omo lagbaja , gbogbo ounti moba se fun e , ki ofi orijin mi.
Posted by Olatiboye Mutiu at 9:48 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Sunday, September 17, 2017


ISORA AGBELEPOTA, ASINA APA EGUN ATI EPE RUN Ao han suratul Masad 71, Ao gun
ewe Akonimora tutu mo ose dudu pelu epo obo die, ao fi omi hantu yen fo, ao fi ako okuta kan si
inu igba olomori kan, ao waa fo eyin ororo kan mo okuta inu igba yen, ti eyin yen bati fo, ao ko
ose yen le lori, ao fi obe tuntun kekere kan tabi obe esu gun ose yii legbe, ao fi omori re de pada,
ao lo gbe pamo fun 41 days, lehin 41 day lao to lo si wo, bi enia ba de idi ose yii ti 41 days koti to
ti o waa losi igba yii wo, eni naa kotun rina mo laye, oju eni naa yio fo ni, ao maa fi obe yen bu si
ori kein kein fun wiwe lalale, Alasasi yio ku, onaa yio si si fun waa, ti awon ota baa fe maa saa
siwa,, won yio ma ku ni. Odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 1:40 PM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

"OSE ATUDE EBE AWON AGBA TI ONA BADI TAN YAN YAN"............Hmmmmmm Omo
iya mi jowo mase fi oju di asiri yi, mawo ti ki kere tio kere, iwo dan wo kio gba wipe Asiri siwa
toun je, atiwipe wibe jebe ti olorun nise...........Ao wa egbo Tude, ao gun pelu odidi atare meta, ti
yio kuna daada, ao wa po papo mo ose dudu, ao wa opolo aye nla meji, ao ko tele ike funfun, ao
wako ose yile opolo yan lori, ao depa ao gbe pamo fun ojo meje, after seven days, ao mafi we lale
pelu omi tolo wooro(EWE NJE BEN KUNFAYAKUN OLORUN LAGBOJU LE)
Posted by Olatiboye Mutiu at 10:18 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

AWURE TODAJU........ao ra monlu Ekirikan ao gbodo naa iyekiye ti won ba pe owo re ni agbódò
ra ao gesi mesan ao se ni lepo niyo pelu ewe ewuro die 'ewe aje pupa' ewe iyalode ao gun po afi se
obe je ti aba ti fe maa je óbe naa ao mo se adura gbogbo ohun ti aba fe si.
Posted by Olatiboye Mutiu at 10:17 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

OSHOLE KEKERE... Oga gbagbe kan, ewe ola die, agbado eyo mesan, Atare aja kan, ao jo papo,
ao fi Milk olope lo lekan, ale ni alo ooo.
Posted by Olatiboye Mutiu at 10:16 AM 2 comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Friday, September 15, 2017


FUN ALAYE LEKUNRERE LORI IRAWO RE Fun Alaye to peye lori irawo ti o mun waye Ise ti
o ye ki o maa se Ojo ti o yeki o maa se Adua Ojo ti o ye ki o maa lo ogun Iru aso toba eleda re
mun Iru ounje to ye ki o sora fun Epe si ori numbers mi O7037422552 or 08029484696 Nigeria
N3000 Others $14.29 USD Pay to thia account Account Name Olatiboye Mutiu Taiwo Account
Number 0117874829 Bank Name Gtb Call me after the transaction
Posted by Olatiboye Mutiu at 9:10 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

AKIYESI PATAKI Opo igba ni awa omo eda nsun gbagbe, opo ninu eda ni koni akiyesi, opo lo ti
lo se ayewo si oro aiye re ti obaa de ibi kan bi won ko ba so wipe awon agba lo nda lamun won
asope iya re ni o waa ni idi oro re, igbamiran won a ni egun idile, ohun ti awa omo eda nfi owo ara
waa faa gan ngba miran gan ju ki awon apapo agba ma da enia lamun lo. Ojo kokan ninu osu loni
ohun ti o nba enikokan wa rin, Irawo ati Ojo ibi maa nda opo eda lamun, ,, opo igba loti lo ogun
dudu sibe sibe pabo lo nja si, boya eleda re ko lo ni ilana unkan be sibe sibe o ko agidi bori oni
dandan iwo naa fe se ogun osole! 1. Irawo Omi, Ewe ki je lara iwo omi, ogun asasi ota ki si saba
ran won, Je enikan ti yio maa saba lo Hantu, tabi ki o maa se Adua si omi, Ebu lilo ki je lara won,
bi won ba fi Millions se Ebu fun won ko le sise, Ose si nma nsise die die lara ju Ebu lo 2. Irawo
Ina. Ha! Irawo yii gbodo je enikan ti o nso ara re kuro lori wiwe ose ni gbogbo igba, Bi ose wiwe
ba po lapoju o da gegebi eni npa ogo ati imole ara re ni, Ebu a maa sise daadaa lara won ju ose lo
3. Irawo Afefe... Awon irawo yi gbodo je enia ti ntera mo adua sise lopo lopo, bi won se ni agbara
to be naa ni won yaa ole (lazy) to, ogun asi maa tete je lara won, besi ni asasi ntete maa nmun
won, won gbodo munra gidi gidi, won ki fe ki won se aseyege eko, enia nla ni won. 4. Irawo
Iyepe, Awon irawo yii maa nje oni suru, won ki tete binu, won gba iwosi sugbon bi won ba binu
tan ibinu won ko dara raa, won ki si fe gbo imoran eda miran yato si ti won, inakuna asi maa ba
won ja pupo, bi iru irawo yii baa tete munra si isori lati ibere pepe aiye won, won ama bori Awon
isoro bi ki owo maa daa lowo won. FUN EKUNRERE ALAYE LORI IRAWO RE, IRU ISE TI O
LE SE, IRU AWON IGBIYANJU TI O LE MAA SE GEGEBI OGUN, IRU ASO TI O YE KI O
MAA WO, IRU AKOKO ATI OJO TI O YE KI O MAA SE ADUA TABI OGUN ETC E PE SI
ORI NUMBERS YII FUN EKUN RERE ALAYE PELU OWO EGBERUN META PERE N3000
Naira N3000 Dollars $14.20 USD 07037422552 or 08029484696
Posted by Olatiboye Mutiu at 8:57 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

EPE TO DAJU Ao waa Ose Kekere kan, ao fi Ato idi waa po po daadaa, ao ju eyo atare kan si inu
iwo etu, ao ko ose yen sinu iho etu yen, ao fi kan enu sepe ti aba fe se. Ti aba fe danwo ao lo si idi
igi kan ao fi epe yen kan enu lemeta ao so wipe Ki iwo igi yi ku ni wakati bai bai, ti aba pada de
idi igi yii yio ti ro ewe. Odaju Lati owo Khosim Hayemu ilu igboho
Posted by Olatiboye Mutiu at 8:32 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

ASEJE OLA TODAJU Igbin meta, Eja Aro tutu meta, Eran malu ao gesi meta, N1000 meta ti
letter T baa bere, ao han Izaja si oju ati eyin owo metetaa, ao jeki o gbe daadaa, ao wa gesi meta
meta ao lo kuna dada pelu ewe Aje, ata ijosi, ao lo kuna, ao fi se won je laseje, ago kan abo oru lao
je pelu adua ola nla, odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 2:19 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

ISORI TOLAGBARA GAN AN. Eran aja, ati eran elede, odidi atare kan totobi dada, opolopo ewe
oriri, ao jo papo, tia ba tan ao fi te owo ifa odu merindinlogun, fi foko mu. OFORE : - Akii fi
asisan pa aja, akii fi igede pa elede, ifakifa kile odu merindinlogun lori ate, ohun ti oba tobi laiye
oriri ni nri, babalawo lo nperi mi nibi, onisegun lonpe ori mi ni ibi, alufa lonpe ori mi ni ibi, oso
ni, aje ni, okunrin ni, obinrin ni, omode ni, agbalagba ni, enikeni tio ba npe ri mi ni ibi oriri bami
riwon mole oriri, ti aba njo ogun yi lowo ako gbodo roro ti ama fi jo tan o.
Posted by Olatiboye Mutiu at 1:18 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Thursday, September 14, 2017


HOW TO USE WHITE CANDLE FOR SPECIAL PRAYER Get a white get 7 white candle,
inscribed this on each candle 787, place the candle in front of you and light all the candle, keep
saying ١٢٠٠٠ ‫ بسم هللا الرحمن الرحيم‬when u are done pack all the remaining and bury them with your
left leg. InshaAllah your prayer will surely be answered.. Please keep praying for our Muslim
Brother and Sisters in Burma
Posted by Olatiboye Mutiu at 3:21 PM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest
TURARI ADUA GBIGBA Turari yii a maa nfi ngba Adua fun awon Enia ti o waa ni ona jinjin,
papa julo Eda ti o baa je ategun ninu won bi enia baa lo Turari yii fun won lati ba won fi se adua,
adua naa ntete maa ngba. Ao waa Ewe gbegbe tutu 201, lori ewe kokan ao maa han Inamo
Amuruhu isa aradan shean anyakululahu kunfayakun ao maa han meje meje lori ewe kokan titi yio
fi pe 201, ao waa ewe Ogbo 201, ao han Salamu kaola mi nrobi roheem meje meje si ori ewe
kokan, ao waa saa kofi gbe daadaa, ao gun pelu awon eronja won yii 1. Iye agbe 7 2. Iye Aluko 7
3. Iye Odidere 7 4. Iye Lekeleke 7 5. Turari Lubansakara 6. Kajiji dudu ati pupa 7. Imi Ojo die
pelu etu ibon gidi ao gun papo daadaa, ao maa fin fun ojo meje pelu gbigba Adua fun eni naa ao si
maa daruko eni naa ati ilu ti o waa pelu ohun ti o nfe, larin Ojo keje Walahi, eni naa yio pe yin
wipe Adua naa ti gba. Ti Adua naa baa gba tan ao pa Odindin Agbo kan fun sara adua naa. Ti aba
ko ti ao baa pa Agbo naa, Eniti o se Adua naa yio maa ri Idiwo kokan. Ale koko ti gba owo eran
Agbo ki ato baa bere adua naa. Akiyesi Ti abaa nfin turari yii lowo ao maa saa suratul Yasin meje
meje lojojumo fun ojo meje, ko gbodo koja ojo meje kosi gbodo maa pe ojo meje
Posted by Olatiboye Mutiu at 12:55 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

IPESE AWON AGBALAGBA Ao wa awo ipese funfun kan, ao waa eko Elewe kan, ao gbe eko yii
sinu awo naa ao ki eyin adie ororo kan si larin, ao won iyo die si, ao se opolopo adua si, wipe ki
Ogun maa je lara mi ejeki gbogbo ogun ma je lara mi, ejeki gbogbo ogun ti mo ba se fun awon eni
maa je lara won, ema se ba ogun ara mi je mo, Adua to ba wuwa ao maa se lehin naa ao gbe lo si
ibi ti won ti maa ngba ipese
Posted by Olatiboye Mutiu at 12:42 AM 1 comment:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Ao han ni igba eyokan pere si oju walah, ao waa fi omi lasan fo, ao maa da omi yii sinu omi iwe
waa ni alale ao ma fi san ara ao maa se be fun ojo meje, ale maa fi we gbogbo awon omo ati iyawo
waa naa. ISORA KURO LOWO AWON EMI OKUNKUN NI
Posted by Olatiboye Mutiu at 12:11 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Wednesday, September 13, 2017


OSE OSHOLE OWO TODAJU Ori eyele 1 Ori Eye owiwi 1 Ori eye osin 1 Ori agbe 1 Ori aluko
1 Ori igun 1 Ori akuko adie 1 Aoko a won ori mejeeje yii sinu igba olomori kan, aowa ewe
etiponola aoso okunmon, aomaawobowa sinu ile tangbe, aowaja 201, laraare, aogun ewe yen lasan
pelu ose dudu..........aowako oseyen sori awon ori mejeeje towani ninu igba, aogbepamo fun 7
days, leyin ojo meje, aomaafiwe laraaro odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 11:56 PM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

ADUA ITUSILE TODAJU Ao raa candle pupa 16, pelu dudu 16, amaa tan ina candle yii circle ara
waa ti aba tan black candle, ao tan red tele be lao se maa tan titi yio fi circle ara waa, ao joko si ni
arin, ao waa maa saa Suratul Yasin, gbogbo igbati abaa ti nsa Ayah Yasin kan ao maa saa Suratul
Fil 71 times be lao se saa titi ao fi pari YASIN ti gbogbo candle yen ba ti jo tan ao ko gbogbo
erunrun to ba ku ao lo bo bole, Gbogbo Enti o bqa ti sa Ogun buruku si wa ri laye, ti won baa si
wa lori epe, ao ma gbo ofo awon ota lokunrin ati lobinrin, ayqfi ti won ko baa se aburu siwq ri
loku. Ti aba ti pari eto yii ao gbe koto to jin daada ao du akuko pupa kan si inu koto naa ao waa da
erunrun candle yen si inu koto naa, odaju
Posted by Olatiboye Mutiu at 5:06 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

OSE OSHOLE OWO TODAJU Iye agbe 7 Iye aluko 7 Ikoode 7 Ori Agbe 1 Ori aluko 1 Ori
odidere 1 Ewe aje Tutu tabi gbigbe Ewe birana tutu tabi gbigbe Ewe aanu tutu tabi gbigbe Aogun
gbogbo re papo aowapomo ose dudu..........Aowa ori aguntan tiwonpa loojo Gbogbo owo paper
tanan pata N5, N10, N20, N50, N100, N200, N500, N1000 Aoko awon owo yen sinu awo funfun
olomori kan.......aogbe ori aguntan si......aoko ose yen siii.........aowagbe ose yen sinu apo asunwon
funfun aogbeko soke...........idiire kogbodo kanlemon. Aomaabuwe laraaro
Posted by Olatiboye Mutiu at 4:47 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

TURARI AWORO TODAJU Ao waa Ori Owawa toni irun kan, Ewe awerepepe gbigbe, Eresile
Ewe Lapa lapa funfun die, Ewe ajeobale gbigbe, Ewe Abifa gburu gburu, Kaji dudu ati Pupa,
Turari Jawal, Igbe Malu gbigbe, egungun ori esin die, ao gun papo ao fi orisi Lofinda 16 po papo,
ao ko sinu awo funfun, ibe lao ti ma bu fin ni Araro. Odaju Samu
Posted by Olatiboye Mutiu at 1:22 AM No comments:
Email This
BlogThis!
Share to Twitter
Share to Facebook
Share to Pinterest

Tuesday, September 12, 2017


OSOLE TO SISE BI IDAN.....Alangba adaripon kan,,Epo obo die,,,imi Ojo die,,atare pelu ikoko
tuntun kekere kan ao du eje alangba yi sori isasun yi ao wa GBE alanga ti adu yi le epo obo ye ati
imi ojo Lori ao Jo papo mo atare ao wa fi po ose ninu isasun naa ao fi abere oporo kan gun ose
yen larin ,,ninu isasun yen naa ni ati malo Ogun yen kiato po lose, ....NB...lojo ti aba koko we
oseyi ti aba WO motor conductor koni gbowo lowo wa omatun bere pe Elo ni change ti amagba ni
.kia gbo owo naa lowore tori ise na ti bere ise

You might also like

pFad - Phonifier reborn

Pfad - The Proxy pFad of © 2024 Garber Painting. All rights reserved.

Note: This service is not intended for secure transactions such as banking, social media, email, or purchasing. Use at your own risk. We assume no liability whatsoever for broken pages.


Alternative Proxies:

Alternative Proxy

pFad Proxy

pFad v3 Proxy

pFad v4 Proxy